E janu kuro loro yi. Gbogbo wa ni GALOMEH ni nigeria. Gbogbo wa la n ganu. Wasiu gan fun ra re na nganu. Affa, woli, babalawo, etc. Gbogbo won lo nganu. Awon kabiyesi to lo gba ghana-must-go labuja na lo ganu ni. Those in the diaspora na, ti won japa, won lo ganu ni. Nkankan ko ni se alhaji wasiu. Esu laalu ati ogun lakaye pelu gbogbo igba irumole ko ni fi alhaji sile
Wahala awon alfa yii topoju ni ile Yoruba kilode gan President gbogbo ilu gan ganu le de another tenure Gbogbo awon min gan tiwon fe dije ni 2027 won ganu botie jepe Yoruba Nation ni awa nfe Gbogbo awa ti anfe Yoruba Nation gan ganu Gbogbo wa tia wa nihin gan ganu Eyin Alfa ile Yoruba go and learn handwork with your osuka Lori,, so that ilara yin ale reduces
Alfa lagbaji osoro opamilerin.awon ti won sope titi 7 days bi wasiu ko ba bebe o maku haaa emaje koribe etiso nisinsinyi tio balo ribe tiko den jepe eyin leshe odoju e niyen.efi wasiu sile o emajeki oku tele momo re.o esanu omo oku orun o eyin Alfa abeyin nio ejeki ogun omin o omota ni enbafaa o efi sile o.
Se K1 ri tiyin ro ni? K1 mon ohun ti won n so, se won pe won ni? Abi koki se awon to pe K1 ni elebo nigba oye K1 na ko ni won lo ganu sile K1? Se Olorun ni awon Alfa yi ni won nfi fun K1 ni ojo meje ki o fi toro aforijin, e kan fe wi K1 tread ni?
Thanks you a lot, wisdom wise talk❤❤❤❤❤❤
😅😅😅😅😅
ALFA GBAYI 💪🤣🤣🤣
E janu kuro loro yi.
Gbogbo wa ni GALOMEH ni nigeria.
Gbogbo wa la n ganu.
Wasiu gan fun ra re na nganu.
Affa, woli, babalawo, etc. Gbogbo won lo nganu.
Awon kabiyesi to lo gba ghana-must-go labuja na lo ganu ni.
Those in the diaspora na, ti won japa, won lo ganu ni.
Nkankan ko ni se alhaji wasiu.
Esu laalu ati ogun lakaye pelu gbogbo igba irumole ko ni fi alhaji sile
Nkan ti wasiu se bad sugbon kia kakun pe ko mo oroso ni torina edarijin.se awon Fulani mo olorun ni won mpa eniyan.
Wahala awon alfa yii topoju ni ile Yoruba kilode gan
President gbogbo ilu gan ganu le de another tenure
Gbogbo awon min gan tiwon fe dije ni 2027 won ganu botie jepe Yoruba Nation ni awa nfe
Gbogbo awa ti anfe Yoruba Nation gan ganu
Gbogbo wa tia wa nihin gan ganu
Eyin Alfa ile Yoruba go and learn handwork with your osuka Lori,, so that ilara yin ale reduces