GBOGBO OMO, ETUNWAGBO OHUN TI OKUNRINYI SO NIPA TINUBU, ILE YORUBA ATI ILU NIGERIA ATI AWON FULANI

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 17 มิ.ย. 2024
  • GBOGBO OMO, ETUNWAGBO OHUN TI OKUNRINYI SO NIPA TINUBU, ILE YORUBA ATI ILU NIGERIA ATI AWON FULANI

ความคิดเห็น • 32

  • @rafiateyiowuawi8526
    @rafiateyiowuawi8526 21 วันที่ผ่านมา +7

    Well said. Baba . I like all what you said. Let those that have hears let them hear and do the needful and defend themselves from the crisis ahead. Prayers can’t stop this calamities that are coming ahead. Go look for what to use to defend yourself. God won’t come down to fight for you . God gave you brains to utilize it accordingly. Take courage and fight for your lives. We only have one life to live on earth . Don’t look back. This is the only one chance we have in this struggle, and we shall succeed with the help of God. Don’t panic God will be with everyone. 🙏🏾 PEACE

  • @peterbamigbade.2685
    @peterbamigbade.2685 21 วันที่ผ่านมา +3

    You absolutely right. Fulanis and hausas are different.

  • @ikeoyeleye3849
    @ikeoyeleye3849 21 วันที่ผ่านมา +1

    Baba wa ese gan ni. E jowo ki ona abayo fun omo adu lawo. Ti je omo yoruba.

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h 14 วันที่ผ่านมา

    Baba lakaye yin ko ni daru o ogbon, imo ati oye yin ko ni ba je

  • @BiodunDina
    @BiodunDina 14 วันที่ผ่านมา

    Thanks for this deep explanation.

  • @estherewetuga8245
    @estherewetuga8245 21 วันที่ผ่านมา +1

    Kabiyesi Olodumare

  • @user-ig6zg4zp4p
    @user-ig6zg4zp4p 14 วันที่ผ่านมา

    Wa ma ripa ,owe lo pa o ni paniyan ,Olorun nkan na ni Yoo gbawa ,sungbon ko wa si bi awon baba wa SE munle to pellu ajoji ti Yoo wa fi maworan ti won o fi pawa tan ,seeri PE awon Awusa gan ti yari PE awon o ba awon Fulani SE Mon ,ka so wipe nigbaye ,awon baba wa o Mon (etekete awon Fulani Wonyi ) So ki YORUBA gbara re sile bayi ni o ,olotu e kuse mo ki yin l lopolopo , Nitorina ki Yoruba dide doju pa fun awon olote wonyi ni ooo YORUBA NATION NOW ,OLODUMARE YOO GBA YORUBA FUNWA

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 21 วันที่ผ่านมา +1

    Adara fun nyin baba wa yi, ogbon o ni kumo yin lori lase Olodumare

  • @user-lo7jy9jf4h
    @user-lo7jy9jf4h 14 วันที่ผ่านมา

    Baba e ku lakaye sugbon se ri omoluabi to mu yoruba bowo fun asiwaju yen o dabi eni pe a ma bo se gbe kan na lati se ohun to ye, ta ba se tan a tun wa gbe wo pada

  • @tawatayo7361
    @tawatayo7361 21 วันที่ผ่านมา +1

    Olorun o ni pa imo e re o seun fun eko ijinle yi .a ma so fun won wipe adura o le se nkankan nibiti a ba ra wa yi. sugbon awon ole to fe thithe o je ki Yoruba mo inu ro mo.

  • @user-br1wr5ch6k
    @user-br1wr5ch6k 14 วันที่ผ่านมา

    Yoruba nation know going back 🎉🎉🎉🎉🎉

  • @ainakehinde583
    @ainakehinde583 14 วันที่ผ่านมา

    That is realllllllll facttttttt

  • @taiwoedunjobi158
    @taiwoedunjobi158 21 วันที่ผ่านมา +1

    Iberu ati òjò lo ndamu awa omo kaaro aajire

  • @user-lx7pq9po7g
    @user-lx7pq9po7g 14 วันที่ผ่านมา

    E ku oro opolo ati ori pipe lori oro ile yoruba. E se gidi gan ni lori imole ti e tan sori oro ati asa yoruba.

  • @festusakapo6212
    @festusakapo6212 14 วันที่ผ่านมา

    You have spoken well Sir, it is time now to take action to fight for our freedom either to start from those that are directing us wrongly as you have said we have got good leaders, but mere selfish politicians who used their position to control their subordinate wrongly. Adari lani, a o lolori to dara bikose awon obayeje, alatenuje ,Oloselu ole, adanikan jopon, awon ika eniyan, Olorun a kowa lona ta Ma fi jagun ti a si ma Segun GBOGBO awon adari buburu ti won pe ara won ni governors, senators, ministers, president. etc

  • @joshuaakafowowe4295
    @joshuaakafowowe4295 21 วันที่ผ่านมา

    Ogba fun o...

  • @felixsaka6776
    @felixsaka6776 14 วันที่ผ่านมา

    Se oro Tinubu ni nwon ma gbe sori titi ojo aiye nwon.

  • @AbbeyKey-mh1lk
    @AbbeyKey-mh1lk 14 วันที่ผ่านมา

    Kini ona abayo bayi ooo baba wa

  • @olufemioguneko4071
    @olufemioguneko4071 21 วันที่ผ่านมา

    Ogbon agba aroba baba itan well done

  • @matthewaderigbigbe4335
    @matthewaderigbigbe4335 14 วันที่ผ่านมา

    kare omoluabi oodua oku lakaye