Imam Ogbomosho ese suruo,eranti ikan ti imam oofa bayii so ninu wasi kan te invite won si,elo tu oro yan gbo ke turo,semo wipe awon idi ayilara won fe ke kose lara oba yiinio ese suruo
Imam should bring himself down,it's should not allow people to push him, been a scholar you are not supposed to give everyone reply otherwise some people will be seeing ur words then use it to qoate you.
Kilode si eyin Muslims ile Yoruba bayi, se a I ni western education to lo fa sisoro bayi.Gbogbo eda to ba deserve aponle ari aponle gba,sugbon aponle kankan ko si fun Alhaji Taliatu Yinusa lasiko yi rara nitoripe o ti tabuku awon toju lo lojo ori,ni ipo ati ni gbogbo ona.Papa julo,emi o ri ibi ti Alfa Akewugba gold ti so Oro abuku si lmam Taliatu Yinusa rara, problem ti eyin Alfas ati lmams Ile Yoruba ni nipe ara yin ko otito oro, e o le so ododo,e o si le dajo ododo,Nigbati lmam Taliatu Yinusa bu odidi Oba Alade(first class Oba for that matter)ati awon agbalagba to ju lo Lori mubari,to tun nse yeye won Lori motorcade,sebi e ngboriyin fun ni.Nigbawo ati ni ojo wo ni iwo abi eyin alfas,lmams gbo ri pe awon Elesin ibile,Pastors, Reverend abi Woli kan nbu awon Oba abi agbagba ilu ri,eyin alfa ati lmams alakatakiti yi na ni.kilode tojepe eyin Alfas ati lmams Ile Yoruba le nko wahala, fitinati ati ogun ja musulumi ati lslam ni Ile Yoruba bayi.ati ijo ti mo ti mo Iwo Kabisanra,ododo ati eto ko jade lenu e ri, sentiments ati oju isaju lo ma fi nsoro. Eniki lmam Taliatu Yinusa pada si ile ko lo ko eko ile ati eko ibanilo ni awujo,nitoripe ko ni eko rara.Ododo oro lo gbo yi to si ma nbiyin ninu.Ki e wa se iranti pe lpo tabi Oye tiwon bafi eniyan je won le yo kuro nigbakigba,ayafi toba jepe eni na loni aye yen abi mosalasi yen. Eronu yin wo,ero ori yin wo,o,eniyan dudu e ko fe ododo oro rara.Abo oro ni eleyi.odigba kan na.
Thank you my brother. JAZAKahLLAHU kahiran fihiduniyah walihakirah for your explanation.
Thanks so much from America
Akewugbagold is a social media alfa,
Long life to the mufti and chief imam of ogbomosho land.
May almighty Allah bless ogbomosho.
You still deh respect akeugbagold 😂😂😂. A very yuzleszzzBoy ni akeugbagold
Akehugbagold Yen Ni igberaga gan Ni, Ko si Le gba iru e
ORO TI BABA WA AKEWUGBAGOLD SO KO PO JU EYIN GAN NI ADARUGUDU
Imam Ogbomosho ese suruo,eranti ikan ti imam oofa bayii so ninu wasi kan te invite won si,elo tu oro yan gbo ke turo,semo wipe awon idi ayilara won fe ke kose lara oba yiinio ese suruo
Imam wey no respect King. Una dey help am fight for respect. Keep clowning.
Imam should bring himself down,it's should not allow people to push him, been a scholar you are not supposed to give everyone reply otherwise some people will be seeing ur words then use it to qoate you.
Nigba wo ni wọn pé Imam ni orúkọ?
Munafiki akeujelede
😂😂😂😂😂
Sobeseluuuuuuuu agba munafiqi
Kilode si eyin Muslims ile Yoruba bayi, se a I ni western education to lo fa sisoro bayi.Gbogbo eda to ba deserve aponle ari aponle gba,sugbon aponle kankan ko si fun Alhaji Taliatu Yinusa lasiko yi rara nitoripe o ti tabuku awon toju lo lojo ori,ni ipo ati ni gbogbo ona.Papa julo,emi o ri ibi ti Alfa Akewugba gold ti so Oro abuku si lmam Taliatu Yinusa rara, problem ti eyin Alfas ati lmams Ile Yoruba ni nipe ara yin ko otito oro, e o le so ododo,e o si le dajo ododo,Nigbati lmam Taliatu Yinusa bu odidi Oba Alade(first class Oba for that matter)ati awon agbalagba to ju lo Lori mubari,to tun nse yeye won Lori motorcade,sebi e ngboriyin fun ni.Nigbawo ati ni ojo wo ni iwo abi eyin alfas,lmams gbo ri pe awon Elesin ibile,Pastors, Reverend abi Woli kan nbu awon Oba abi agbagba ilu ri,eyin alfa ati lmams alakatakiti yi na ni.kilode tojepe eyin Alfas ati lmams Ile Yoruba le nko wahala, fitinati ati ogun ja musulumi ati lslam ni Ile Yoruba bayi.ati ijo ti mo ti mo Iwo Kabisanra,ododo ati eto ko jade lenu e ri, sentiments ati oju isaju lo ma fi nsoro. Eniki lmam Taliatu Yinusa pada si ile ko lo ko eko ile ati eko ibanilo ni awujo,nitoripe ko ni eko rara.Ododo oro lo gbo yi to si ma nbiyin ninu.Ki e wa se iranti pe lpo tabi Oye tiwon bafi eniyan je won le yo kuro nigbakigba,ayafi toba jepe eni na loni aye yen abi mosalasi yen. Eronu yin wo,ero ori yin wo,o,eniyan dudu e ko fe ododo oro rara.Abo oro ni eleyi.odigba kan na.
You are seriously sick.. not even read ur gilbrish