Nitootọ bibiire ko ṣee fowora. Are kare, ọmọ ọkọ ni ẹ. Ki Olodumare fun Baba wa, ẹgbon wa Justice Moshood Abbas ni ẹmi gigun. He's a great Leader. #Jogun-omi.
Baba kan ló jáde lára àwọn èèyàn Ààrẹ Gani Adams ló ní 2001 pé Lájì Abass yẹn sì wa l'ọmọde tọ́ ń wọ pátá káàkiri.. Mo rẹ̀rín títí pé eléyì mà gọ̀ o..!! Kò tiẹ̀ mọ ẹni tó njẹ́ Ààrẹ Lájì Abass rárá.. 😂😂😂.
Go on Soun Aare.... Awodi jeun epe sanra ❤❤❤
Congratulations Many more bigger honour to come your way sir 👑
Bibi ire ko se fi owo ra,Aare opitan ile Nigeria.Ki emi Ola o gun Oluko agba,Onibode Ile Yoruba.
That is so true . Many people often look at me anytime I talk about history and Yoruba cultural heritage.
Nitootọ bibiire ko ṣee fowora. Are kare, ọmọ ọkọ ni ẹ. Ki Olodumare fun Baba wa, ẹgbon wa Justice Moshood Abbas ni ẹmi gigun. He's a great Leader. #Jogun-omi.
Ààrẹ Laji Abass, ẹ ṣeun tí ẹ gbà pé k'ógun mí. Ṣùgbọ́n ẹni ọ̀bẹ bá nídí yóò mọ̀ pé ojú àpá kò lè jọ ojú ara.
Congratulation. A ku orire ti oye Aare Opitan Ile Yoruba, oye a mori, aaamiin ase.
Eku eto sir kin ni oje ti yoruba ki fe gba funrawon
E ku eto OMo baba mi . Aliwo/ Motala/ Oke adu state. OMo Ojuyaye lawa
Aare Opitan, inu buruku koni bie, oponu loma rinu ti koni bi, oponu na manbe ti kiigbo, ese o
Olotu olorun yoso agbara dotun ❤❤❤❤❤🎉
Pls you are not only for Ibadan, but for Yoruba land.
Used basket to fetch water?. I believe you cos we still have some powerful people in Yorubaland.
CONGRATULATIONS 👏🏿 ON YOUR NEW TITLE! WELL DESERVED ❤
E ku eto Olohun a wa pelu yin.
Baba kan ló jáde lára àwọn èèyàn Ààrẹ Gani Adams ló ní 2001 pé Lájì Abass yẹn sì wa l'ọmọde tọ́ ń wọ pátá káàkiri.. Mo rẹ̀rín títí pé eléyì mà gọ̀ o..!! Kò tiẹ̀ mọ ẹni tó njẹ́ Ààrẹ Lájì Abass rárá.. 😂😂😂.
Kemiola ogun sir.
Good.
This is my fifth years
❤❤❤❤❤
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
❤