Gbogbo eni to fe so awon oluranlowo awon omo mi di ota won, ogun orun kolu won, Oluwa ba mi ta won lofa iku, edakeda to fe so oluranlowo awon omo mi di ota won, Oluwa fi iku kolu won, ki o ba mi run won danu loruko Jesu
Gbogbo ogun oganjo oru ninu aye emi ati awon omo mi, Orun gbe won mi loruko Jesu, gbogbo iparapo ise okunkun ninu aye emi ati awon omo mi, ni oruko Jesu ina run won danu, ni oruko Jesu gbogbo asasi oganjo oru lara mi ati awon omo mi, maa baje, Oluwa ba je, baje loruko Jesu
I connected myself and my job and my family and my children in to this prayer in Jesus name amen
I connected my family and my job to this prayers Hallelujah hallelujah hallelujah ogo ogo ogo nifun Baba Amiñnnn
I claimed all the prophetic declarationsl, breakthrough, blessings and upliftments for my children in Jesus name
Sir it a blessing to meet you I will never remain the same all my prayers are answered
Amin Jeeesu
It a very big priviledge to meet you today in saki sir my life will never remain the same
Amen Amen 🔥🔥
Gbogbo eni to n fi ala da mi pada sehin tomotomo, ni oruko Jesu emi won lo si, Oluwa ja okun emi won loruko Jesu
Gbogbo eda to n gbogun lati pa mi lomo togotogo, Oluwa je ki emi won lo si, Oluwa ba mi ja okun emi mi loruko Jesu
AMEN. JESU
Gbogbo eda to n dena ogo awon omo mi, ogun orun ja okun emi won loruko Jesu
Gbogbo eni to fe so awon oluranlowo awon omo mi di ota won, ogun orun kolu won, Oluwa ba mi ta won lofa iku, edakeda to fe so oluranlowo awon omo mi di ota won, Oluwa fi iku kolu won, ki o ba mi run won danu loruko Jesu
JESU
Baba Authority please visit us in Badagry axis sir from Oladunjoye Adenike Olufunke
Gbogbo ogun oganjo oru ninu aye emi ati awon omo mi, Orun gbe won mi loruko Jesu, gbogbo iparapo ise okunkun ninu aye emi ati awon omo mi, ni oruko Jesu ina run won danu, ni oruko Jesu gbogbo asasi oganjo oru lara mi ati awon omo mi, maa baje, Oluwa ba je, baje loruko Jesu
Jesu o seun oooo, mo dupe oore
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, eyin epe ati egun ti ko lero, e jade lara mi, e jade lara awon omo mi loruko Jesu
Gbogbo epe ati oro odi ti a sosi mi ati awon omo mi, ni oruko Jesu ba ina jade lara mi, epe ati egun jade lara awon omo mi loruko Jesu
And I left all d way from Abk to saki 😪nd I knew no one here in saki it’s well ooo😢
I couldn’t see myself there 😢😪