IKA NI YIN ..... July 18, 2024

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 14 ต.ค. 2024
  • Sunday igboho in

ความคิดเห็น • 149

  • @ogoatiagbara1
    @ogoatiagbara1 2 หลายเดือนก่อน +15

    Gov. Makinde alabosi Ika onijekuje onimotara enikan eniyan ni, Sunday igboho you are the hero of Yoruba land we really appreciate you

  • @okodogbegraceolapeju1021
    @okodogbegraceolapeju1021 2 หลายเดือนก่อน +8

    CSI we love you. God bless you

  • @bilikisubolajokoamoje2707
    @bilikisubolajokoamoje2707 2 หลายเดือนก่อน +4

    Sunday ighoho is covered with the BLOOD OF JESUS CHRIST NAME AMEN

  • @biamondgroups4448
    @biamondgroups4448 2 หลายเดือนก่อน

    Thank you, bold and beautiful

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 หลายเดือนก่อน +12

    Won ma gbe omo Sheyi Makinde ati iyawo re lagbara Olorun, igba yen lo ma man nkan ti o nse oun

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 หลายเดือนก่อน +14

    Seyi Makinde kini awon omo re nse ni America .Ti o ko ba surport sunday Adeyemo lgboho lori oro Fulani ni oyo state olorun yio pale re mo kuro ni office governor tio wa yen kio to pare tenure re ni Oyo state ni agbara olorun amin ase Edumare kio lo ba awon ebi re fulani ni North...

    • @ajibola3052
      @ajibola3052 2 หลายเดือนก่อน

      For a very long time I know that guy called makinku is a traitor to omo yoruba in oyo state

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 หลายเดือนก่อน +4

    Awon ijoba munje munje, gbogbo eyin ti ewa leyin awon apaniyan ibinu Olorun asokale sinu idile gbogbo yin ni ase educate, awon oselu ooooole

  • @yorubawuyitv1234
    @yorubawuyitv1234  2 หลายเดือนก่อน +8

    Awon ika ęni ibi

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 2 หลายเดือนก่อน +10

    THE LORD OF HOST WILL DESTROY ALL THE ENEMIES OF YORUBA LAND AND DESTROY ALL THE ENEMIES OF CHIEF SUNDAY ADENIYI ADEYEMO IGOHO OOSA LORUKO JESU

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +4

    Ekuirore my sister YORUBA Wuyi orisah Wuyi obatala Wuyi Sango Wuyi Oshun Wuyi ekuse tankuntaun opolo yin Koni joba laseeedumare ♥️♥️♥️♥️♥️♥️♥️👍

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +6

    YORUBA Nation no going back laseeedumare Ibukun ni fun Ori EDE mi YORUBA ❤️♥️❤️♥️❤️♥️❤️♥️🙏

  • @feliciaogundana2230
    @feliciaogundana2230 2 หลายเดือนก่อน +3

    Alabuku ni Seyimakinde and Emir of Iwo are brothers no doubt of their relationship awon oponu eda. Rederede lo ma gbehin Seyimakinde in Oyo state.

  • @okodogbegraceolapeju1021
    @okodogbegraceolapeju1021 2 หลายเดือนก่อน +6

    Seyi Makinde, alabosi ati alaimoore eda ni oo

  • @OkeowoTaiwo
    @OkeowoTaiwo 2 หลายเดือนก่อน +2

    May God continue to bless Sunday igboho oosa for us

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +1

    ABENI OMO o se paro eni to ba ma paro Abeni a de waju federal government se you on next show my sister ❤❤❤❤❤❤

  • @MakunGrill
    @MakunGrill 2 หลายเดือนก่อน +4

    Ẹ mọ pe Governor makinde wá lábẹ́ PDP, tani olórí wọn? Mr Atiku Fulani. Ordered from the above.

  • @bilikisubolajokoamoje2707
    @bilikisubolajokoamoje2707 2 หลายเดือนก่อน

    GOD will uphold you

  • @modupekosoko1176
    @modupekosoko1176 2 หลายเดือนก่อน

    Awon olorun Eda,
    Family of Ajinigbe.
    Seyi makinde alausa fulani karabani.

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 หลายเดือนก่อน +6

    Awon oponu, won man boya won madi ola laye, won nsare 2027, awon ika eniyan Olorun amun gbogbo yin

    • @yorubawuyitv2833
      @yorubawuyitv2833 2 หลายเดือนก่อน

      Iwa won niyen awon alainironu

  • @JosephAyanwola
    @JosephAyanwola 2 หลายเดือนก่อน

    Gbogbo eyinalagbara omo yoruba ti e nse oogun fun awon olori ile yoruba wonyi,ti okan won fi kiri laigbo ohun ti anso.emaa pa idi ore da fun wonooo.

  • @agnesshelle9639
    @agnesshelle9639 2 หลายเดือนก่อน

    Gbogbo awon to ngba abode fun awa Omo Yoruba. Olorun lo ma dajo fun gbogbo won ati awon EBI won loruko jesu

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน

    My sister YORUBA Wuyi orisah Wuyi obatala Wuyi obatala Wuyi Sango Wuyi.Eku ataro enu yin ko o ni kan laseeedumare eku eto OLORUN OBA a ma wa pelu yin oooooo Laseeedumare 🙏♥️

  • @jamesitaronbi3889
    @jamesitaronbi3889 2 หลายเดือนก่อน +7

    AIYE NYO GBOGBO OTA YORUBA LENU ALALE ODUA ASE IDAJO

  • @AdepojuGabriel-we8ng
    @AdepojuGabriel-we8ng 2 หลายเดือนก่อน

    Gbogbo awom to nyo awa Yoruba lenu olorun yio bawa finira yo aye yin lenu Aamin ase

  • @OkeowoTaiwo
    @OkeowoTaiwo 2 หลายเดือนก่อน

    Iya mi yoruba wuyi,eku eto ma yoruba nation is a must

  • @toyinsalau7298
    @toyinsalau7298 2 หลายเดือนก่อน

    Well done ❤

  • @ajibola3052
    @ajibola3052 2 หลายเดือนก่อน

    Igboho la wa mo o

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +2

    AWON OBA wa ko soro nipa Sunday IGBOHO OSSA rara ooooo OGA hunnnnñn

  • @bilikisubolajokoamoje2707
    @bilikisubolajokoamoje2707 2 หลายเดือนก่อน

    Weldone sister

  • @MosunmolaAbiona
    @MosunmolaAbiona 2 หลายเดือนก่อน

    Yes you are right 👍👍👍💯💯💯💯💯

  • @gbengakolade6366
    @gbengakolade6366 2 หลายเดือนก่อน +4

    Sunday Igboho sọpe ki awọn ajinigbe ninu Igbo ilẹ yoruba kúrò nínú. Igbo wa, Seyi Makinde ni rara, ṣe Seyi lo ní kí wọn máa jiwà gbe ni, ṣe awọn fulani lo nṣe ijoba le lori ni? Igberaga ma ti gbe Seyi buruku yẹn wọ ọ, Seyi Satani.

  • @Sayitasebe
    @Sayitasebe 2 หลายเดือนก่อน

    Emini yio se , Seyi nkan kanri mole bi agbo emini yio se

  • @agnesshelle9639
    @agnesshelle9639 2 หลายเดือนก่อน

    Se Governor Seyi Makinde ,of Oyo State ko ni Iyawo ni tabi ko bi Omo ni .Sebi obinrin ni Iyawo re, ti gbogbo won ko le soro nipa gbogbo ajalu ti nlo ni Oyo State. E jowo e ba wa ba OKO yin soro nipa lati fi Sunday Igboho Osha sile

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi Makinde, o ma sofo gbehin aiye e ni. Gbogbo Oun to n ‘ pa e lerin ma pada pa e le kun ni, ti o ba ja wo lorun Sunday Igboho ati gbogbo omo Yoruba la pa po.

  • @atinukeserifat793
    @atinukeserifat793 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi makinde ti je tan. Alale Yoruba o ni je ki o wole elekeji.

  • @mosunmolaolayide3986
    @mosunmolaolayide3986 2 หลายเดือนก่อน +1

    AWON OMO ALE ONJEKUJE LO POJU NINU AWON OLORI WA.

  • @taiwowemimo1856
    @taiwowemimo1856 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi Makinde yi kolanu rara iya loma je gbehin aiye re lagbara Olorun Amin jesu

  • @atinukeserifat793
    @atinukeserifat793 2 หลายเดือนก่อน

    Awon agba buruku ni opolopo awon agba to wa Nile Yoruba. Awon gangan ni ika, atubotan yin o ni daa gbogbo eyin omo Yoruba ti e Fe sowa di eru Fulani lagbara olorun oba.

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +1

    Governor Seyi Makinde se e wayin wa ni se e in sere ni tabi e se hunnnnnn

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 2 หลายเดือนก่อน

    Makinde ni Mału pelu Fulani lo se fe ki won pa awon omo Yoruba tan, gbogbo bi Seyi Makinde ba se to Sunday Igboho si ati awon Omo Yoruba si , be lo ma ri fun Seyi Makinde ,ati gbogbo Iran Makinde Olorun Edam lowa, abe gbo Ode ti on de fun Sunday Igbo, lowo re , titi de Iran keta ati Eleran. Ma ba ise buru ku to nse lo’ Idajo ale lori re. Elę se ko ni lo lai jiya . Elefanta Sunday a bere lowo gbo yin

  • @saudatadeyemo3607
    @saudatadeyemo3607 2 หลายเดือนก่อน

    Free sunday igboho osa

  • @bilikisubolajokoamoje2707
    @bilikisubolajokoamoje2707 2 หลายเดือนก่อน

    Maalu landlord of yoruba farmers land

  • @VictoriaShoyemi-o9r
    @VictoriaShoyemi-o9r 2 หลายเดือนก่อน

    Omo ale ti dapo mo omo oju lowo Yoruba ,Olorun amu wa Kuro lowo awon Eni ibi, chief Sunday ema ma Bori awon OTA yin ni ase Edumare ati Baba wa Prof Akintoye

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน

    Governor Seyi Makinde ni ❤❤

  • @ayoolababatunde4710
    @ayoolababatunde4710 2 หลายเดือนก่อน

    O dabi eni pe ori i gbogbo awon oloselu paapaa awon gomina ile Yoruba tiwa yii ti daru,o dabi i pe orogun iyaa won ti n fedi si won ,nitori oro won ko fe ye mi mo.

  • @MichaelAlake-b3l
    @MichaelAlake-b3l 2 หลายเดือนก่อน

    Yoruba Nation no going back.

  • @oregbesanmulikat8292
    @oregbesanmulikat8292 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi makinde olorun ma da fu yin oooo

  • @awoniyisherifat6829
    @awoniyisherifat6829 2 หลายเดือนก่อน

    E ku eto Oluwa a maa fun yin se o

  • @kennyogunkoya3634
    @kennyogunkoya3634 2 หลายเดือนก่อน

    Awon governors ati closely ati awon agbagba Ile Yoruba alabosi ni won.Olorun ma doju ti won .ltan aye won ni won nko sile bayi .Gbogbo enia mama ka leyi ti won balo

  • @victoriaolababy7756
    @victoriaolababy7756 2 หลายเดือนก่อน

    Awon n won ran awon funlani nise

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 2 หลายเดือนก่อน +5

    EKU ISE TAKUNTAKUN YORUBAWUYI

  • @OlarewajuIlesanmi
    @OlarewajuIlesanmi 2 หลายเดือนก่อน

    Oloribuu ni seyi makide pasan nbo fun

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis 2 หลายเดือนก่อน

    Ori Sheyi Makinde ti daru. Awon Alale yio dajo.

  • @taiwowemimo1856
    @taiwowemimo1856 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi Makinde ti gba owo lowo awon Fulani to npa enia won e o ni jere lashe Edumare Amin

  • @adeleyeabimbola1432
    @adeleyeabimbola1432 2 หลายเดือนก่อน

    O buru o bu ogiri seyi makinde o dee maa ri ibinu Olodunmare laipe laijina lagbara alale Ooodua

  • @saudatadeyemo3607
    @saudatadeyemo3607 2 หลายเดือนก่อน

    EMI. E Agun lagbara olorun
    Lagbara gbogbo alale gbewa nipa lagbara odmare

  • @AdelekeAjayi-mw5wm
    @AdelekeAjayi-mw5wm 2 หลายเดือนก่อน

    ólle seyi amugbo

  • @SolaAkin-zi6kt
    @SolaAkin-zi6kt 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi makinde ro igbeyin, bibeli so wipe opin san ju ibere lo, mawa IBINU OLORUN Tete SE atunse loni, ipo yio pin lojokan ISE rere ni yio ku tiyio soro Lola, seyi makinde ro igbeyin

  • @victorbabalola5432
    @victorbabalola5432 2 หลายเดือนก่อน +1

    Nje Yoruba gidi ni Seyi Makinde? Efura o!!!

  • @agnesshelle9639
    @agnesshelle9639 2 หลายเดือนก่อน

    Sunday Igboho Osha daruko Governor Seyi Makinde

  • @Stella-O
    @Stella-O 2 หลายเดือนก่อน

    Ika man seyi makinde oloye de ma buyi fun ni gbogbo igba ti o ba soro

  • @oluremibabawale4344
    @oluremibabawale4344 2 หลายเดือนก่อน

    WE COULDN'T SEE THE END OF THAT VIDEO.

  • @omoyelesamson2150
    @omoyelesamson2150 2 หลายเดือนก่อน

    E jeki awon eniyan wa ma a ba ise lo. Ki won sise won. No government agent will enter the bush at night. Our warriors should not allow the threat to discourage them

  • @Sayitasebe
    @Sayitasebe 2 หลายเดือนก่อน

    Ha ogbooro , legbe ago owode

  • @nikeonatunji2186
    @nikeonatunji2186 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi makinde o gbagbe oore ni
    Eyi ti o ni enu lati soro Lori oro igboho se bi ibi ti di eni igbagbe bayi o si ranti isele kogi ki o beru Olorun.

  • @AjokeSilamia
    @AjokeSilamia 2 หลายเดือนก่อน

    Gov. Makinde ise yin ma to pari

  • @johnOLULEYE
    @johnOLULEYE 2 หลายเดือนก่อน

    Inu won o le dun,tori ibi eje alaise ni won ti nje onje won

  • @OdebisiEsther-gk9lf
    @OdebisiEsther-gk9lf 2 หลายเดือนก่อน

    Kilode, ti wo Gov yi send wa yi wa pada ,se bi wo na Latin yin tele.maa se a se re o no to Ajimabi.

  • @Rebecca76001
    @Rebecca76001 2 หลายเดือนก่อน +1

    Omo ale gomina ni, awon ole onijekuje

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน +1

    AWON agbagba wa na ko so unkankan rara OGA ooooo hmmmmmmmmm

  • @KehindeoseniSaliman-ou4jt
    @KehindeoseniSaliman-ou4jt 2 หลายเดือนก่อน

    Yoruba nation no going back

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 2 หลายเดือนก่อน

    OMO okunrin na la ya saa OGA ooooo hmmmmmmmmm Afi ki OLORUN OBA saun wa ooooo

  • @AdesolaOladeji-d8m
    @AdesolaOladeji-d8m 2 หลายเดือนก่อน

    Were ni awon eyanyi

  • @ayodeleadegbile8639
    @ayodeleadegbile8639 2 หลายเดือนก่อน

    Tori Governor 'Ladoja ni Seyi Makinde fi korira Chief Sunday Igboho. Makinde ti wa gbagbe pe adanitan ti danitan ki agunbaje to de, nigbati agunbaje de o ba wa l'owo atunnise. Seyi Makinde ahere nigbehin oloko. Ti o ba jawo l'oro Sunday Igboho ijoba re ko ni ni isinmi. Iwo na ko ni fi ara re se ijoba re.

  • @sikiruoluwasegun6804
    @sikiruoluwasegun6804 2 หลายเดือนก่อน

    Atokun eku eto.gbogbo awon adari wa nile ile Yoruba lagbara olorun lagbara awon alale gbogbo won ma sofo tomo tomo won ma ku akurun tebi tara won. sasa niku mama sawonpa sasa tiran tiran pelu ase edumare Yoruba nation is the only way. freedom for Yoruba nation no going back Oduduwa agbe gbogbo wa koni gbe awon omo ale Odale

  • @bilikisubolajokoamoje2707
    @bilikisubolajokoamoje2707 2 หลายเดือนก่อน

    Love you for loving and caring for yoruba nation

  • @femijohnson5008
    @femijohnson5008 2 หลายเดือนก่อน

    Sniper awon were yi

  • @Stella-O
    @Stella-O 2 หลายเดือนก่อน

    Sunday lgboho sa ki won soro re ota awon oloselu lo je nitori ona atije je won Lodi yen ohun ti won ma je ko je ki won gbo won gbo sungbo oju gbogbo won ma bo

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 หลายเดือนก่อน +1

    Seyi Makinde ti o ko ba fi sunday Adeyemo lgboho sile kio gba wa lowo Fulani ori re fe buru...lgbati sunday Adeyemo lgboho lo si lgangan iwo seyi Makinde weere yi na lo tako . Bomb ti Fulani fi pa awon enia ni lbadan kilo se si...se omo ale lbadan ni e seyi Makinde. Se oyun fulani ni mama re gbe fun baba re ni???

  • @Ọmọọlọrunmoṣọpẹ7991
    @Ọmọọlọrunmoṣọpẹ7991 2 หลายเดือนก่อน

    Won buru, won bu ogiri

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 หลายเดือนก่อน

    Eyin Yoruba politicians tie wonu egbe imule lati ma fi iya je awa omo Yoruba iku esin ni gbogbo yin ma ku danu ni agbara olorun amin ase Edumare

    • @BD-nn3fq
      @BD-nn3fq 2 หลายเดือนก่อน

      Ase

  • @kennyogunkoya3634
    @kennyogunkoya3634 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi Makinde

  • @abidemimoses3865
    @abidemimoses3865 2 หลายเดือนก่อน

    Yoruba wake up
    Yoruba Eji, Emaa sun
    Kosi gbogbo eleyi ni Ibo land

  • @moniladephilips7439
    @moniladephilips7439 2 หลายเดือนก่อน

    Seyi Makinde ati gbogbo ota Yoruba ma jiya gbeyin ni. Their generations will eat from the suffering. Wicked people.

  • @oluwasesanajayi2298
    @oluwasesanajayi2298 2 หลายเดือนก่อน

    D town is call ogboro in oyo state

  • @GaniatAlakeAlli
    @GaniatAlakeAlli 2 หลายเดือนก่อน

    Sheyi makide

  • @AdepojuGabriel-we8ng
    @AdepojuGabriel-we8ng 2 หลายเดือนก่อน

    Pelu ogo olorun atubo won koni suwon lagbara olrun

  • @sunshinesm5657
    @sunshinesm5657 2 หลายเดือนก่อน +2

    Se awon alele ko le nan seyi Makinde ni daku ni😂😂😂😂😂😂😂.
    Abi weere nse seyi Makinde ni.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 2 หลายเดือนก่อน

    Gbogbo eyin Yoruba politicians tie ntako sunday Adeyemo lgboho lori oro Fulani ofo lomi efo nse ofo ni gbogbo yin ma se danu tirantiran ni agbara olorun amin ase Edumare...

  • @taiyeajiboye3968
    @taiyeajiboye3968 2 หลายเดือนก่อน

    Ika ni gbogbo eyin politician omo Yoruba ati president,e beru olorun eyin olori ni ile Yoruba,fulani ko JE fi awon omo won sile fun ijiya rara.olorun a gba agbara lowo gbogbo yin.alale ile Yoruba a bi gbogbo yin.eleda Sunday igboho a ja fun Lori eyin Nigeria government.

  • @saudatadeyemo3607
    @saudatadeyemo3607 2 หลายเดือนก่อน

    ADUNNI ADE

  • @Stella-O
    @Stella-O 2 หลายเดือนก่อน +1

    Se seyi makinde ko ri awon oko oloko ti fulani ko awon malu won je

  • @userOlowu
    @userOlowu 2 หลายเดือนก่อน +1

    Seyi makinde alabode eda eniyan nii

  • @sulaimonadigun7235
    @sulaimonadigun7235 2 หลายเดือนก่อน

    O tin clear

  • @agnesshelle9639
    @agnesshelle9639 2 หลายเดือนก่อน

    Some of the 🐄 COWS belongs to the OBA (KINGS) of OYO STATE, is why the Governor &the Kings cannot talk there's GOD oh

  • @ruthoyeronke5629
    @ruthoyeronke5629 2 หลายเดือนก่อน

    E mo fi won sepe mo , alale a mo da fun awon agbeyin bebo Sunday Igboho .Be niyo ri lase Edumare.

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 2 หลายเดือนก่อน

    Malu Seyi Makinde lodo Fulani lo je ki o korira Yoruba., aso we’re nko rojo,lai mo eni too ma na, they think they are going to live forever. Won ti gba gbe Olorun, won ja ye bi eni ti ko si Eni to ma mu won,be Olorun ko da Eni ti ko le mu, gbogbo awon, Bale ati awon Bebe ti won tori Malu npa omo Yoruba? Ki won lo dana sun gbogbo won ki won lo nn owo mału won lorun, Eku eto.

  • @JosephAyanwola
    @JosephAyanwola 2 หลายเดือนก่อน

    Ki gbogbo awon omo ilu maa ya loo pa awon ika eda buruku yan see ninu ile won ati olopa won ki e maa pawon danu.

  • @MariaAjibodu
    @MariaAjibodu 2 หลายเดือนก่อน +1

    Ika.lawon.gomina.wa.onije.kuje.ni.won.won.ti.gba.nkan.lowo.wao.ni

  • @agnesshelle9639
    @agnesshelle9639 2 หลายเดือนก่อน

    Gbogbo awon Oba ati awon Ijoye to wa lori oro idibaje to nlo ni Oyo State ko mo wipe Idajo nbe lodo Eledunmare