"Kini Orire Ti Ija Esin Ko Ba Ile Yoruba?"Baba Akeugbagold Binu Jadetan Lori Katikati Ija Esin Tonlo

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 13 ต.ค. 2024
  • Sheikh Muhammad Taofeeq Akeugbagold Binu Jadetan Lori Katikati Ija Esin to nlo lowo Laarin Musulumi, Onisese,Ati Christaini ,alaye Baba Akeugbagold Naa Kun gege Lori Oro Ile Yoruba ati IJA Esin Ati Kini Orire Ti Ija Esin Ko Ba Ile Yoruba gaaaan !
    Kini Orire Ti Ija Esin Ko Ba Ile Yoruba?"Baba Akeugbagold Binu Jadetan Lori Katikati Ija Esin Tonlo
    Subscribe to this channel and turn on post notification © Follow Good example Tv on Facebook © Instagram @Good Example © Tiktok @Good Example.

ความคิดเห็น • 13

  • @solabolaji5364
    @solabolaji5364 วันที่ผ่านมา +7

    Baba Akewugbagold, e ma se abosi o! Pastor ko ni nkankan ṣe pelu ọrọ to wa nilẹ yii. Awon aafaa olowo Saudi ni ki e ba sọrọ. E ba Adepoju ati Adegunwa ati awon saabe lehin won sọrọ ki won ye te esin yooku loju. Eyin naa le n kigbe ogun. Onisese ko fun wa ni wahala afi lslam ologunde yii

  • @adewilliams8
    @adewilliams8 วันที่ผ่านมา +7

    Ma pariwo si wa leti, awon alfa yin ni ki o lo waasi fun kii se awon omo oko Yoruba onisese baba nla wa.

  • @salamiridwan9292
    @salamiridwan9292 วันที่ผ่านมา +2

    Alabosi alfa

  • @susanbose8130
    @susanbose8130 วันที่ผ่านมา +1

    Baba you they try but you we have to explain oooo because una people don spoiled everything

  • @rychirychi3315
    @rychirychi3315 วันที่ผ่านมา +2

    Sobeselu, Mr. President, we are tired of your abosi

  • @sundayoyinalabi9755
    @sundayoyinalabi9755 วันที่ผ่านมา +1

    Baba ,eyin musilim ni e da gbogbo whala yi sile

  • @TerraPlattetl
    @TerraPlattetl 22 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Awon omo yin lofa aini ise na lo fa se won le se nonsense yi ni Uk abi us ni ti won ti nfa ise ti bills tan fe sanwa nile

  • @EnebeMakanjuola-ds9pj
    @EnebeMakanjuola-ds9pj 7 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Alfa Akewugba gold you are always on point but, please mention the names of the alfas that are spoiling other religions & let them stop the nonsense hence forth that is the last solution.

  • @abrahamaugustus1619
    @abrahamaugustus1619 วันที่ผ่านมา +1

    Awon Alfa yin ni ki e bawi,tabi ki e kilo fun,awon bi Adegunwa ati Adepoju.
    Pastors tabi Christians ko lowo ninu gbogbo nkan to nlo lowolowo.
    Adepoju pelu Adegunwa ati bebee lo ni ki e ko ni janu

  • @susanbose8130
    @susanbose8130 วันที่ผ่านมา +1

    Baba you they try but you we have to explain oooo because una people don spoiled everything

  • @susanbose8130
    @susanbose8130 วันที่ผ่านมา +1

    Baba you they try but you we have to explain oooo because una people don spoiled everything