Kini Oba ghandi lọ se ni gombe | Pst Adeboye sọrọ | Asiri tu! Oloye warri lo bá ọmọkùnrin 16yrs sun
ฝัง
- เผยแพร่เมื่อ 9 ก.พ. 2025
- Kini Oba ghandi lọ se ni gombe | Pst Adeboye sọrọ | Asiri tu! Oloye warri lo bá ọmọkùnrin 16yrs sun #ogbenibobby #sundayighoho #tinubu #arisetv #oriyomihamzat #obasolomoni #sundayighoho #trendingnews #esabod #channelstv #yorubanation #iammoreyorunathannigeria #vdm #verydarkmannigerianfamous #bobrisky #kemibadenoch #yeyedaratalk2
Iba tikkel me, i tikkel you oooo, ❤❤❤❤from ilu mi NETHERLANDS 🇳🇱👏🏽🙌👊🏾👍🏾🤛🏽
Oga ooooooo omo odo thank God I really like my Madam here I'm from libay one love❤
Ogbeni Bobby iba gboingboin lanrofa aditi alariwo of yoruba nation angbadun e ❤❤❤❤❤❤
Eku ise takuntakun, Yoruba nation no going back ❤❤❤❤❤
Baba Adeboye, agba yin a dale ooo, e seun ti eforiji ooo❤❤❤❤
Ogbeni bobby eku eto GOD WIL CONTINUE TO BE WITH YOU AND UR FAMILY CONTINUE THE GOOD JOB
AMEN ❤❤❤❤ and you too sir
E kale oooo buroda mi, Ogbeni Bobby,Aaya ati gbogbo ile❤❤❤❤
Ogbeni B eku ise o,hmmm gbogbo iroyin ti a ngbo lojojumo pelu orile ede yi komu inu eniyan dun rara,afi kolorun sanu wa kiakia ki Yoruba Nation tete bo si,ynñgb,lre o.❤❤❤❤❤❤❤❤
Ekuise sir Yorubaland will free one day one day
Yoruba nation no going back ❤❤
Happy Sunday o Ogbeni Bobby ati Aaya. Ose Ayo fun wa o loruko Jesu.
Oju ferese 😂😂😂😂fun iroyin sharp sharp👏🏽
Iba GBOGBO EEEE😂😂😂😂❤❤❤❤
Weldon my dear brother ogbeni Bobby gbogbo abiamo aye olorun konifi inaomo jowa
Inaomo kikuro Lara obi o ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Amin loruko Jesu.
Ogbeni Bobby, ijoba loni opolopo ebi iwa buruku tohun sele ni orile ede Nigeria olorun a sanu gbogbo wa,yoruba nation ire ooo❤❤❤❤
Iba Allegedly 😂😂😂😂
A ku isinmi ooo, se e lo josin ni owuro yi? 😂😂😂
❤❤❤
May God have mercy upon Nigeria, eku ise ogbeni Bobby, always enjoyed your news.may continues to strengthen you and aaya everyday ❤❤❤❤❤❤.
❤️❤️❤❤❤❤❤
Iba 'royin. Happy new week. ❤
Yoruba nation no going back
Awon eniyan dajuo ika kinni awon obi awon omo yi lese ti ofi mapa omo meta fulani se tiwon ijoba se tie awon ara ilu se tiwon Olorun je ki yoruba daduro o❤❤❤❤❤❤❤
😢
Figure 8, sepe sepe❤❤❤❤❤
FREEDOM IS PURE LIBERTY FROM SLAVE AND SLAVERY
Ogbeni Bobby emi fall in love pelu Awada re ni ti ede abinibi re pelu wipe orewa ni Omo okunrin😂😂😂 ori re wu Abi 😂😂😂😂😂bi gari. It is well❤❤❤❤
Ogbeni Bobi well done. Eku ise ilu. News yin o nfi asiri ilu han fun wa lopolopo. Olorun aranwa lowo o. ❤❤❤❤
Iba akede Yoruba Nation no going back. Thanks for the good work. Odabi pe awon Nigeria force ti nsise fun Lagos boy jagaban 😂😂❤❤❤❤
Oluwo ati Mufti iwo ti gun igi koja ewe bayi. Awon Oba ti ifa o mu o soro mo, lodi lodi ni won ma n'hu iwa, bii ki won ko ogun ja ilu lo ma n'se won. YNNGB. ❤❤❤❤❤❤ Oluwole from Dallas TX
Ogbeni Bobby ekaro, iba oruko po. Thank you for always taking us to the koko of Nigeria. Olopa exchange is their best work, both in report and person.
Sunday Majasola Adisa Adeyemo a.k.a Igboho Oosa unkutable Alapaji1 a şoro pęlu ikoro ati iporuru okan ♥ nitori pupo n'inu wa koni a ni ir'ori boti wun nki o ri
Oba Gandi one of rccg senior pastors God Almighty will direct his paths eku ise o
Iba apanilerin, iba opaka, oko opekeeee 😄
Cheeeeesssseeeeeee, Mushin Olosha, idi ishin, Challenge ni Ibadan😂😂😂😂😂😂😂😂😂
Well done 👍. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.
Ogbeni Bobby ati Aaya Plc, Olorun ko ni dawo duro lati ma a bayin se e ooo. Ooto oro ni oro lori credit facilities, banks in abroad always pre-approved people with good credit rating for more money on your credit cards.
Happy Sunday to you Ogbeni Bobby.
Afi Ki Olorun gbawa lowo awon Olopa isonu ti o nsise ni Nigeria. Ole gbe ole gba nio. Ki gbogbo abiyamo sora ki won si bojuto omo won ki won to sowon di Agege. YNGB ❤️❤️❤️❤️❤️❤️❤️
Ogbeni Bobby, a ku eto, nkan nlo lorile ede Nigeria, i listen to Dele Giwa story iku Dele taba ile ota ba oko, sugbon babangida ni orun lara lori oro iku Dele,
Beeeni ❤
Yoruba Nation no going back ooooooooo
O Bobby a Ku eto olomo ilu Toni o, adupe fun alaafia yin, Lori owo ti ijoba nya awon akeko ti won NI kon San nigbati won nsise, eyin a jeki won da Ise sile, ❤❤❤❤🎉🎉🎉 e BA mi ki Aaya
Oluwaseun Lori alaafia yin, ki Olorun SE alekun, O Bobby, bi Iwo BA SE rere ara ki o a ya ho, lo difa fun Ogbeni Togun, idajo Eri Okan lo buru ju lo, o ju idajo Ile ejo, YNNN, ❤❤❤🎉🎉🎉, e ki Aaya fun mi
Amiiin ni Oruko nla Jesu Kristi
Ogbeni Bobby ati Aaya again, oro ijoba ligeria yen, pelu awon omo ligeria yen, oro ile ti a t'omo iri lo ma wo. Gbogbo oun ti ijoba ligeria nse lo ma lehin.
Cheeseeeeee mushin ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Haaaa I Kunle abiyamo a ni Fiji sunkun omo Lori ko Jesu omo meta oluwa Dani wa ooo e ma yase ooo ose yi a san wa oooo❤❤❤❤❤❤❤
Ogbeni Bobby e ku ise takutakun olorun a ma ba se o ko ni re enikankan wa ni oruko jesu amin
Ogbeni bobby Kayefi nla leleyi Oku to ti ku Ha kini ilu wa da yi Eru ba wa o a ba jo ti awon enia ma nsin oku won sinu ogba ile won. this is serious eyin Alfa eyin onisese e dide o ki won to ba aiye yi je tan e gba o
Iru ajosepowo ni Oba Gandi ni pelu awon Oba Hausa / Fulanis
Obgbeni Bobby, please what can we people do to make yourba Nation work, please help us ask Mr Sunday Igbo.
Because this is the time to let us know what we can do to join them.love from there oko awa arugbo, from Tx
Enu ologbeni yi ma koba oooo😂😂😂
Nigeria ni won ti nra ile laini Ise lowo, Gbogbo e na Lori Iroo ni o, Iree oo, O daaro
Salaam 😊 ❤❤❤❤❤❤
❤❤❤❤❤❤
Beeni, CREMATION WILL BE BETTER, I have seen a lot of ASHES OOO THROUGH MY WORK , AS A CARER
Dad Moki Aya ati oga reeee
Ha omase o. Pls continue enlightenment on freedom sir . Opolopo ni o mo itumo ominira o. Se oye ki won tun ba won maa mura idibo pelu gbogbo ijiya yi ?
Afi ki Olorun fi oye ye won o.
Mo nki Brother mi Ogbęni Bobby Ayaa ati gbogbo awa ti a wa ni ori ikanni wa yi ęmi gbogbo wa yio se opolopo l'ori ilę alaye ni Oruko nlà Jesu Kristi Amiiin
Ogbeni Bobby,ATI Aaya the Good Lord will continue to be your strenght, infact its really sad for all this bad offenses in our country (NIGERIA) INUNIBINI KII SE AIMO IWAWU. GBOGBO JULO AWON OSELU TI BA GBOGBO OFIN IRO JE (YORUBA NATION LA NFOJU SI )🎉🎉🎉❤❤❤ OLORUN A GBA FUN WA 🎉🎉🎉🎉🎉❤❤❤
Gbogbo iroyin Naijiria yi ma je kayeefi fun wa o. Ki Olorun saanu wa o. ISI ga ju o.
Iba ifę sowapo❤❤❤❤🎉
E ku ise takuntakun Ogbeni Bobby. BRICS has many countries that has joined them - about 31 countries, I don't think India's exist can dissolve the union. Let us wait and see with what Trump is doing to many countries. Yoruba Nation now now no going back. Thanks for this news program, it helps me to sleep every night. Love you and Aaya plenty ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Baaaaa ganusi cheeeeeeeesssseeee mushineeeee e ku otutu oooo a ba wa lara mu ko ni se owo odi si wa lara oooo❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤ aaaya nikan ni o ni love yi nitori e njowu aaaya lana 😢😢😢😢😢😢
❤❤❤❤❤❤❤❤
O’ Bobi, E kuu Ajale o, Olorun a ba wa de Igbinyanju yin laade o, E o ri Ogo yin loo dalee Aameen Allegedly nio, awon Olopaa ti n Kopaa ninu Iwaa Odaran ni Nigeria tipetipe, won maa nse Opapa parada, Oro Lori Owo ni o, Won ti paa awon Omo yii , before inu firisa, Ikunle bimo a fiwon Han, In Shal Allah, Aameen, love you Salaam
❤❤❤❤❤❤❤❤❤
The Nigeria children are very talented in many areas of professional development. The main problem is the Nigeria Government don’t value their knowledge they have. In other Countries they will encourage them to be productive and bring more economic growth to their countries.
Oluwa sèun nitoriti Aanu rę duro titi lailai Amiiin Adupę pupo l'owo Olorun Obà oké fun Ore Ofę rę l'ori gbogbo wa T'omot'omo T'omo'mo T'idile T'idile Ogo ni fun o l'oke orun aye alafia inu rere si eniyàn Amiiin
Ogbeni Bobby ati haaya salafia ni o,otun wunmi lati korin laleyi ooh,se ri baba Adeboye baba dada ni won,won ti sora won di jesu toni pe,baba dariji won nitori won omo ohun ti won se.lati okusuna leko😂😂😂
Thank you Mr Bobby . I appreciate your feedback on the matters of the three children found in the fridge. Hope they bring us more autopsy results. What I thinking maybe someone that knows their parents and their movements. It maybe the family members or their neighbors . But God will reveal the person that did this horrible things. People let get Yoruba Nation and straighten all these maladies. Auto zero tolerance for the bad people.
Iba ayo mi kun. Iba gbe won d’ebe. Iba opapa parada. E kú iyanju o. Orile èdè Yoruba á gbè wa o. E seun bi e se n mu inu wa dun. A n gbádùn eto yii pupo. God will bless u. Igba ti Yoruba Nation bá dé, won kò ní fi wa sàwátì ni oruko Jesu. Omo Oduduwa dide! Bó sípò ètó rę, ìwo ni ìmólè, ògo adúláwò. Yoruba Nation!!! Together we will win ❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
❤️❤️❤️❤️❤️❤️
Gbogbo awa abiyamo aye o ni fi awon omo wa pa wa lekun ni oruko jesu amin 🙏
Eku ise o Iba ifesowapo, Olorun a maa bawa se o,agbole alayo wa yi o ni baje lase Eledumare o, ibadara ki awon odo wa wonyi maa fii ogbon ati imo ti won ni won yi se ohun to n wuni lori ju jibiti lo,ife owo aniju, wahala ni o. Olorun a je kan gbo.
Ogbeni Bobby, akoko niyi fun wa lati bere si ni ma ko ofin ti amamaa lo ni orile edewa. Ki Oba mo agbara re,ki looselu mo agbarare Yoruba Nation, no going back from Minnesota
Ogbęni Bobby kini nkàn ti o nşęlę ni Orilę-ede Nigeria 🇳🇬 na ki won pin Orilę-ede Nigeria ki kaluku malo ni tirę ni Ayo idunnu ati alafia ko ju bęlo rarà
Iba allegedly, ati ijo ti won ti se rituals pelu yahoo talo ti lowo ju Aare tabi Gomina lo, won kan waste awon enia nitori lehin oreyin won ma mu won, e joo ki baba Togun so fun wa eni ti o fun Dele Giwa ni leta bomb lojo na, Yoruba Nation now 2025 odun ljewo awon agbagba ni, alale a gba ile fun wa nirorun ❤❤❤❤❤❤❤🎉🎉🎉🎉🎉u are strengthened with AAYA
Ogbeni Bobby eku etooo OLORUN ama bayin se ooo, Baba ADEBOYE fi oro omo yen se bi eniti o bu Oba DAFIDI ninu Bibeli ni oo, [2 SAMUEL 16 vers5 to13] [ SAMUEL 19 vers16to23]
Iya po ni omo Nigéria ofi beru iku
Whenever I visit Nigeria and see the Police with their long gun I fret and shiver. I have never seen gun with the Police for all the years I have been living in England.
Awon omo Ogbomonso po ni ile ahusa
Ogbeni Bobby mewa nsele ni Nigeria kolorun ma fiso sowa tomotomo tebi tara
Amen 🙏
Ekasan Ogbeni Bobby esi ku ise. Mo ti saaju wipe daddy G O ko ba awon ara ita wi bi kose pe , awa awon omo won ni wonni ki a gba awe pelu alaye yekeyeke. Won ko si fi ipa mu wa. Kilo kan awon ti kii se redeemites nipa iyen?
Ogbeni Bobby, enu awa YORUBA O KO RARA, to be REALISTIC, i mean it.
Exactly 💯, you're very correct ma'am
Enuwa KO sugbon atenuje ni onpa awon eniyan waku lo
atiwipe omo ale tipoju nin arin wa
Ogbeni Bobby igbati won mu yaya bello na o nrerin ni that means o ni baba isale ko si nkan ti won ma fi se won kan ma phone ni pe kan release e
Awon omo Ogbomoso pò ni Gombe lopolopo.
Boya, oba lo bè awon omo Ogbomoso wo ni Gombe ni o.
Ominnira no goin back
Oro buruku leyi o . Ejowo ilu ibo na ti wu iboji bi eleyi ?
Ha eyi sumi o !!!
Ewo mi o tile mo nkan ti mo le so mo.😮😮😮😮
Ogbeni Bobby bi mo ba raye japa kuro ni Nigeria o di gbere sokoto werey
Ogbeni bobby Ni London won se Camera si gbogbo Burial ground won won de ni staff to nsise mbe won fence e round pelu gate ki council jo o kan se ogba si burial ground pelu gate tori eleyi je ohun ibanuje fun ara ilu.
Ogbeni bobby E jo talo ma gba wa ni nigeria yi gbogbo ibi to nsele yi ti npoju won sin won de brial lati ge ori this is getting too much
Oga olopa ododo oro le so oo
All this yoruba king's don't disave to be king wen do you
See igbo king's for Noth 😢😢
Ogbeni Bobby Oro Gloria Okon gangan lo pa Dele Giwa won kan waste ogbeni yen danu ni
Ijoba gan lo eniyan
Aşę Edumare
The news about the chief that knack that inocent boy was in Warri, and the hotelier that knack four 16 yrs old school boys in Lagos is a different case entirely, ❤❤❤❤
@Ọ́gbẹ̀ni Bọbi mí tòótọ́ my darlington! Àwọn ènìyàn yín ní Ọṣun tí ganu sì inú òṣèlú (If you can't beat them join them) kò I ye wọ́n ní yóò yè wọ́n lọ là! 💃💃💃💃💃Àánú wọ́n ó ṣe mí ó ní àdúrù gbogbo ariwo wá. 😮 Mó tí pín ó, Àmín
"Darlington " ! Okay o. Awa a f'owo mu Aaya. Ko sa maa be sile lojojumo. 😂😂😂
Greetings ❤
Iba Allegedly ati Aaya a ku isinmi oni oo.Opolopo iwa buruku awon odo wonyi ni Naijiria awon ijoba ni o faa oo. Kosi eto kankan fun awon odo wonyii awon naa fe ona abayo fun ounje oojo eyi lo fa ti awon iwa buruku yii fi npo sii lojojumo oo.Ominira Yoruba nikan ni ona abayo oo Oluwa a gba wa ooo.
Ori awon oku yi, a ti di egungun yanyan
Eku eto Ogbeni bobby ati Aaya
Chife yen buru Gan ni
Obi omo tie omba aye
Alaye je ,ki ijoba fi owo ofin gbe
Lati ile ni musulumu ti buru sugbon awon baba wa ni igba yen won nse musulumu pelu isese,isese tan nse gan ju esin musulumu lo,won o lodi si isese ni igba yen ohun le se ro wipe esin Alafia ni ki se esin Alafia oooooooo,ogbeni Bobby ese o😂😂😂
Ogbeni Bobby o dara bi e ti nmu awon past video yen o lati ma ta waji bi a ba ti nsun lo o e seun o
Ogbeni Bobby a wa ma nse iranti awon oku wa ni church wa
Awon olojelu ile yoruba ni eeyan buruku tio ni ife ara ilu tin fa ifa seyin fun yoruba nation
Sharia Curt loye ki won ti dajo won
Omo Yoruba ko gbon ninu iya ti o je won. Olorun ni kan lo le gbawa. Yoruba nation now no going back.
❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤⭐⭐⭐⭐⭐⭐⭐⭐⭐⭐👍👍👍👍👍👍👍👍👍👍