AWỌN MUSULUMI TI WỌN JI GBE NI ṢOKOTO L'ỌJỌ ODUN ILEYA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 19 มิ.ย. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...
  • บันเทิง

ความคิดเห็น • 21

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 หลายเดือนก่อน +9

    Mama Alaroye you are too much

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 หลายเดือนก่อน +5

    IYA ALAROYE E KU OHUN AFI KI OLORUN GBASAKOSO FUN NIGERIA O TOJU SU WA O KI OLORUN SAMU WA LOPOLOPO A SESE FUN WA LOLA OLORUN AAMMIINN

  • @moyomoyo4860
    @moyomoyo4860 หลายเดือนก่อน +12

    Please, divide Nigeria now and let everyone go in their separate ways for peace to reign.

  • @mariamasie9329
    @mariamasie9329 หลายเดือนก่อน +3

    Eyin lo kan, ema moju to

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 หลายเดือนก่อน +2

    Se awon ijoba ma so pe awon o gbo nkan to nsele ni abi won kan da aguntan tori pe ona ti won gba wole ni Ko je Ko won mo nkan ti won le se

  • @Oodua-ii
    @Oodua-ii หลายเดือนก่อน

    You are one of the best pundit anywhere. Much love and respect. Please show love with thumbs-up for mama o soju mi koro.

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 หลายเดือนก่อน +2

    Know more one Nigeria they should divide Nigeria ooo maybe that one will be solution

  • @Omoayo7066
    @Omoayo7066 หลายเดือนก่อน +3

    Olori buruku ni awon ijoba tani nilu Nigeria 🙉

  • @kehindebellosikirubello989
    @kehindebellosikirubello989 หลายเดือนก่อน +1

    This is what Buhari cause when he was on site

  • @moyomoyo4860
    @moyomoyo4860 หลายเดือนก่อน +10

    We don't want one Nigeria again.

  • @EngrOlaFrederick-kd5sn
    @EngrOlaFrederick-kd5sn หลายเดือนก่อน +6

    One Nigeria na SCAM

  • @olabisiayodele3322
    @olabisiayodele3322 หลายเดือนก่อน +2

    Ti eba laju sile ti fulani Olorun ba gba ijoba oruko yin Ko ni pare ninu iwe itan

  • @yusufmuriano1867
    @yusufmuriano1867 หลายเดือนก่อน +1

    pls we are begging. let us go our separate way na. one Nigeria is not working na. abi kinni gbogbo eleyi na

  • @iloriabiodun9682
    @iloriabiodun9682 หลายเดือนก่อน +4

    Esin ofo
    Yoruba ronu

  • @_Abdussalama
    @_Abdussalama หลายเดือนก่อน +2

    Sokoto kii ṣe orirun Musulumi ni Nigeria. Ko si ẹni ti o ti awọn afẹmiṣofo leyin nipa iṣẹ aburú wọn. Awọn ijọba ni o ṣeṣẹ wọn d'oju ala. Aimọkan yin pọ gan, madam.

    • @user-cl1vj6vc5j
      @user-cl1vj6vc5j หลายเดือนก่อน +2

      Nibo wani orirun musulumu ni Nigerian???

    • @_Abdussalama
      @_Abdussalama หลายเดือนก่อน

      @@user-cl1vj6vc5j Islam kọkọ de Nigeria ni agbegbe Borno lọdọ awọn Kanuri (Bariba) ki o to di odun 1000. O de ilẹ Hawusa ati agbegbe ilẹ Yorùbá ni ọdún 1300 si 1400. Ìjọba lo fun Sultan ile Sókótó ni ipò olórí lẹyìn òmìnira orilẹ ede náà.

    • @user-cl1vj6vc5j
      @user-cl1vj6vc5j หลายเดือนก่อน

      @@_Abdussalama esehun adupe oo

    • @Alaroyeonlinetv
      @Alaroyeonlinetv  หลายเดือนก่อน +2

      @@_Abdussalama Ẹyin naa ti sọro naa, pe ijọba lo fun Sultan ni ipo olori awon musulumi. Sultan yii lo n kede igba ti gbogbo musulumi maa bẹre aawe ati igba ti wọn maa ṣọdun. Ẹyin naa sa mo bẹe. Ṣokoto si ni Sultan n gbe, nibi ti Uthman Dan Fodio to bẹrẹ Jihaad jokoo si. Tabi ki i ṣe nitori pe Dan Fodio ni awon Hausawa yii ni Gobir ko ṣe musulmi daadaa lo ṣe gbogun ti wọn! Tabi ki i ṣe awọn Kanem ni Borno yii ni ija buruku ṣẹlẹ laarin awon atawon ọmo Uthman Dan Fodio ni. Ki lo de to jẹ awọn Fulani musulumji Ṣokoto ni wọn di Emir ni gbogbo ilẹ Hausa? Abi kin ni itumo Emir, ki i se Amir-li-mumiin (Olori awon Mumini) ni wọn ge kuru bẹe ni! O si daju pe ẹ ko tẹ le iroyin igba ti awon Boko Haram ati afẹmiṣofo bẹre nile wa, bi ẹ ba tẹle wọn ni, ẹ ba mọ ohun ti awon eeyan bii El-Rufai, awon bii Sheik Gumi atawọn mi-in nilẹ Yoruba nibi paapaa sọ lori ọrọ wọn. Ẹni to ba n ṣe iwadii ọrọ ki i ṣe alaimọkan, nigba miiran, tọhun a maa nimọ ati ọgbọn ori ju awọn ti wọn mọ ọna kansoso lo, nitori ti eeyan ba jẹ oniwadii ọpọ ọna ni yoo mọ, ohun to ba si mo ni yoo fi ṣe agbekalẹ ohun to ba fẹẹ sọ jade. Ọrọ rẹ paapaa yoo si yatọ patapata si ti alaimọkan.

    • @_Abdussalama
      @_Abdussalama หลายเดือนก่อน

      @@Alaroyeonlinetv Ko eyii ti o kan mi pẹlu awọn ọdaran Fulani abi ẹya mii bi ko ba n ṣe aiwulo ijọba ti ko ṣe iṣẹ abo bi o ṣe yẹ.
      Islam ti wa ni Nigeria fun aimọye ọdun ki wọn to bi Dan Fodio. Oun kan fi ìjọba Fúlàní rẹ jọba ni. Ko tunmọ si wipe ibẹ abi latari rẹ ni Islam fi gberi ni agbegbe ti a mọ si Nigeria lonii. Ẹ ku Iṣẹ Iroyin yin o.