Aare Opitan, won Le kira won bee, aboru aboye, ife lonje bee, kaparapo koyewa lanfe, ti elegun ati olobatala ban bara won se, emaje ka turawa ka pelu itan. Ti gbogbo wa banpe ara wa lomo Oduduwa tabi omo Awolowo tabi Orunmila. Gbogbo omo Yoruba Le perawa lomo Ibadan tabi omo Eko tabi ilu min. Ife ni.
Ijinle Ede Awon Omo Oko Ootu/Yoruba Ni Gbolohum Aboru,Aboye ,Abo Sise,O ye Ki a Mo wipe Awon Elebo lo seda Ede Yoruba Ati ijinle Oruko Orisirisi Ti A Nje Lode Oni
Baba mi LAJI ABBAS, you're Saying the truth and I believe you 100%, we all watch many of our Native movies that actually exhibit those things then.. I believe one thing in my life that if there's no Original things, there shall be no fake of it... meaning every fake things comes out or copy from Original. So I used to watch real tradional Yoruba movies then where they will Use human being for ritual for the betterness of a particular village to makes peace to reign in that land.
Bí a bá wo àwọn ìran Lárúbáwá tàbí àwọn ìran Júù, á ò rí wípé ìlànà ìkíni ẹ̀sìn wọn (tó gbajúmọ̀ jù) ni wọ́n ń fí ń kí ra wọn. Fún àpẹẹrẹ, "Shalom Aleichem" ni àwọn Júù fí ń kí ra wọn (wọ́n gba ẹ̀sìn tàbí wọn kò gbá). Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn Lárúbáwá ń kí ra wọn pé "As-salamu alaykum.” Kò wá burú bí àwa ìran Óótù náà bá ń kí ara wa ni ìkíni Ifá wí pé "Àbọrú Àbọyè Àbọṣísẹ." Gbogbo Onísẹ̀ṣé ò bínú sí ìkíni nà. Bí a bá dé àwùjọ àwọn ẹlẹ́sìn kàn-àn-kan tó kù ní Ilẹ̀ Yorùbá, a ó sì ma kí wọn ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀sìn wọn. Ìfẹ́ ni a fẹ́ láwùjọ Yorùbá. Nítorí nà, mo kí gbogbo wa pé Àbọrú Àbọyè Àbọṣísẹ o.
People that are born in 1974 should have a little knowledge about this sir....what you are saying is true but what we are trying to do now is to turn the table around and doing things the good ways.
Aare opitan don't mind this people they don't know anything about Yoruba history they are small children and once again they are not ready to learn from there master
Baba Laji Abbass, even so many American films displayed how they use human beings, most especially women for ritual. So sad we deny our heritage. Even in Bible, there is a place where a king sacrifice his first son when fighting the isrealites.
Aboru ,Aboye Abo Sise is Generally For Yoruba / Ootu And the Recipient will /Might Return the Greetings Ogbo Ato yin o.Not really Pertaining to a Particular Set of Traditional Religions,Because Most of them Are Aboru/Aborigine ,Aboye /Survival ,Abo Sise (ASE) If you’re able to to Break Down Those Yoruba Words You will Be Able to Translate It Very Well,Yoruba Language is Generally for Elebo People
@Aree opitan please can you bring the evidence to back your claims up where they use people for sacrifice in Yoruba land? Not them say or them say, bring the evidence and prove, you can’t just speak without concrete proof
Aare Opitan, won Le kira won bee, aboru aboye, ife lonje bee, kaparapo koyewa lanfe, ti elegun ati olobatala ban bara won se, emaje ka turawa ka pelu itan. Ti gbogbo wa banpe ara wa lomo Oduduwa tabi omo Awolowo tabi Orunmila. Gbogbo omo Yoruba Le perawa lomo Ibadan tabi omo Eko tabi ilu min. Ife ni.
Mr aboruboye, eo si funwa ni itan tiyin
Ijinle Ede Awon Omo Oko Ootu/Yoruba Ni Gbolohum Aboru,Aboye ,Abo Sise,O ye Ki a Mo wipe Awon Elebo lo seda Ede Yoruba Ati ijinle Oruko Orisirisi Ti A Nje Lode Oni
Baba olohun aku yin lowo sir ❤
Baba mi LAJI ABBAS, you're Saying the truth and I believe you 100%, we all watch many of our Native movies that actually exhibit those things then.. I believe one thing in my life that if there's no Original things, there shall be no fake of it... meaning every fake things comes out or copy from Original. So I used to watch real tradional Yoruba movies then where they will Use human being for ritual for the betterness of a particular village to makes peace to reign in that land.
More Likes for Chief Historian please.
Bí a bá wo àwọn ìran Lárúbáwá tàbí àwọn ìran Júù, á ò rí wípé ìlànà ìkíni ẹ̀sìn wọn (tó gbajúmọ̀ jù) ni wọ́n ń fí ń kí ra wọn. Fún àpẹẹrẹ, "Shalom Aleichem" ni àwọn Júù fí ń kí ra wọn (wọ́n gba ẹ̀sìn tàbí wọn kò gbá). Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn Lárúbáwá ń kí ra wọn pé "As-salamu alaykum.” Kò wá burú bí àwa ìran Óótù náà bá ń kí ara wa ni ìkíni Ifá wí pé "Àbọrú Àbọyè Àbọṣísẹ." Gbogbo Onísẹ̀ṣé ò bínú sí ìkíni nà. Bí a bá dé àwùjọ àwọn ẹlẹ́sìn kàn-àn-kan tó kù ní Ilẹ̀ Yorùbá, a ó sì ma kí wọn ní ìbámu pẹ̀lú ẹ̀sìn wọn. Ìfẹ́ ni a fẹ́ láwùjọ Yorùbá.
Nítorí nà, mo kí gbogbo wa pé Àbọrú Àbọyè Àbọṣísẹ o.
Oluko Agba! Eku Iwaju.
❤🎉Best Of All The Time ❤😊
People that are born in 1974 should have a little knowledge about this sir....what you are saying is true but what we are trying to do now is to turn the table around and doing things the good ways.
Aare opitan don't mind this people they don't know anything about Yoruba history they are small children and once again they are not ready to learn from there master
Baba Laji Abbass, even so many American films displayed how they use human beings, most especially women for ritual. So sad we deny our heritage. Even in Bible, there is a place where a king sacrifice his first son when fighting the isrealites.
Continue to tarnish Isese and Yoruba culture because of religion
You are not okay
@@tunadese your father and mother are not ok eyin oloriburuku omo irankiran
Aboru ,Aboye Abo Sise is Generally For Yoruba / Ootu And the Recipient will /Might Return the Greetings Ogbo Ato yin o.Not really Pertaining to a Particular Set of Traditional Religions,Because Most of them Are Aboru/Aborigine ,Aboye /Survival ,Abo Sise (ASE) If you’re able to to Break Down Those Yoruba Words You will Be Able to Translate It Very Well,Yoruba Language is Generally for Elebo People
Thank you Are have been waiting for you to respond

Oloribuku nie