Oriki Ikoyi by Eyinju Eledumare

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 3 ต.ค. 2021

ความคิดเห็น • 32

  • @user-xd3ql1db3h
    @user-xd3ql1db3h 7 หลายเดือนก่อน

    Ìkòyí èshó,
    Ọmọ agbọn iyùn,
    Ogun ajaaiweeyin lọ meso wù mí,
    Ogun ojoojumo lo mú kilee wọn sú mí lọ,
    èshó kí gba ọfà lẹ́yìn,
    Gbangba iwájú ni wọn fí gbaọta,
    Ọmọ oni Ìkòyí akoko,
    Èyin lọmọ àgbà tín yàrun ọ̀tẹ̀,
    Ọmọ ogun lérè jọjà lọ,
    Ìkòyí ọmọ Aporogunjo,
    Ìkòyí gbéra ń lé ó dìde ogun yá,
    Ọjọ́ Kínní tó nìkòyí kú,
    Ṣùgbọ́n mo kúrò lọmọ agbekórùn lọ oko,
    Wọn gbélé wọn bo onìkòyí
    Àgbède gbede onìkòyí lọ sùn ibè,
    Àtàrí onìkòyí Kò sún ibè,
    Àwọn lọmọ aṣíjú àpò piri dàgbà ọfà sọ fún,pofún yóò yọ dàgbà ọfà sile,
    Ọmọ aku fepo tele koto,
    Ọmọ igunnugun balẹ̀ wọn a jori akalamagbo balẹ̀ wọn a jẹdọ.

  • @ajayitimothy1588
    @ajayitimothy1588 4 หลายเดือนก่อน

    Do oriki for iju itagbolu

  • @anthonypedro-kf6ci
    @anthonypedro-kf6ci ปีที่แล้ว

    Love your voice dear. Your greatness will know no boundaries in Jesus mighty name. Ride on love

  • @Eyinju_vocals
    @Eyinju_vocals  2 ปีที่แล้ว +5

    You're welcome onboard to Eniolaeyinjueledumaretv.
    The sky is the beginning

  • @AjibadeKazeem-um3pp
    @AjibadeKazeem-um3pp 11 หลายเดือนก่อน

    🥰🥰

  • @Kazeem-ip9qu
    @Kazeem-ip9qu 11 หลายเดือนก่อน +1

    Oseun omodaada

  • @adeyimikaebraheem7129
    @adeyimikaebraheem7129 9 หลายเดือนก่อน +1

    God bless you ma 🙏 ❤ 😘 ♥ 💕 💛

  • @ologoeriakehusolaadeniyi3942
    @ologoeriakehusolaadeniyi3942 ปีที่แล้ว

    Amazing with sweet voice,👍👍,plz do Egba own plz🤦❤️

  • @olopadeodunayo
    @olopadeodunayo ปีที่แล้ว

    Olorun o ni back on you je, good job my sister. Can you do the oriki for Ajayi? I love Yoruba heritage but all this things is going to extinction gradually. Thanks for upholding our culture.

  • @GastonAdewale-rm1ik
    @GastonAdewale-rm1ik ปีที่แล้ว

    Nice

  • @lawalibrahimadewale9768
    @lawalibrahimadewale9768 2 ปีที่แล้ว

    Ride on baby gurl...aye will not take your voice away from you INSHA ALLAH 🙏

  • @amaoahmadomoyeni2574
    @amaoahmadomoyeni2574 2 ปีที่แล้ว +1

    BismiLlãhir-Rahmānir-Raheem.
    Bãrakallãh feek

  • @Mista-FOODMAN
    @Mista-FOODMAN ปีที่แล้ว

    So smooth with it 🔥🔥🔥

  • @omotoyegomez6193
    @omotoyegomez6193 ปีที่แล้ว

    This is amazing

  • @Mista-FOODMAN
    @Mista-FOODMAN ปีที่แล้ว

    Bless you ❤

  • @asakedechantingdiva1541
    @asakedechantingdiva1541 11 หลายเดือนก่อน

    Your voice though ❤

  • @Avatarifypyh
    @Avatarifypyh ปีที่แล้ว

    Good evening Miss eniola… please how do i connect with you… i beed you to make me a video and i can know what your requirements are

  • @CollyBest97
    @CollyBest97 ปีที่แล้ว

    God will bless you

  • @D_Spicity
    @D_Spicity ปีที่แล้ว

    ❤️❤️

  • @The_blessing_bamigboye
    @The_blessing_bamigboye ปีที่แล้ว

    Weldone dear

  • @al-itqaanschool5952
    @al-itqaanschool5952 2 ปีที่แล้ว

    Nice work on your ending.

  • @sunnybig6141
    @sunnybig6141 2 ปีที่แล้ว +1

    So that we can nigociate thanks

  • @user-nm6of3xz9u
    @user-nm6of3xz9u 9 หลายเดือนก่อน

    Nice one

  • @bashirbello8885
    @bashirbello8885 2 ปีที่แล้ว

    Nice voice

  • @awopegbasofiat615
    @awopegbasofiat615 2 ปีที่แล้ว

    Pls can I get the lyrics

  • @darelaoga2436
    @darelaoga2436 2 ปีที่แล้ว

    i love you so much oriki oyo please

    • @GazellezMSP
      @GazellezMSP 2 ปีที่แล้ว +1

      Excellent!!!!! . . . your contact info is needed on your profile.

    • @Eyinju_vocals
      @Eyinju_vocals  2 ปีที่แล้ว

      They are all on ig

  • @yorubanimitv1675
    @yorubanimitv1675 2 ปีที่แล้ว

    Nice one