STRONG WARNING TO THOSE ABUSING THE THRONE OF SOUN OGBOMOSO OBA GHANDI AFOLABI OLAOYE

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 21 พ.ย. 2024

ความคิดเห็น • 6

  • @josiahilori4028
    @josiahilori4028 10 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Ilu ogbomoso ati agbegbe re ki se agbegbe ti ani keni ma se arifin si. Adupe lowo Olodumare fun Oba olye, ologbon ti Eledumare fun Ogbomoso. Omo ogbomoso ojulowo ki fi abukun kan Oba ilu kankan. Kin lo wa de ti enfi abuku kan ilu Ogbomoso. Oro ti Imamu Agba Ogbomoso da sile, oro idile re ni. Ko kan Oba Ghandi Olaoye. Ki Iman Agba ki olo se atunse ni idile re. Ko si ninu itan Ogbomoso ati agbegbe re wipe Musulumi, Kritiani ati Onisese ba ara won ja. Awon ti ki se omo Ogbomoso eja wo kuro loro oro Ogbomoso. Oba Ghandi Olaoye, Oba ti o ni ife ilu re ni gidigidi ni. NI owo odun kan ti olo ni ori ite baba re, oti se ribiribi si ilu Ogbomoso ati agbegbe re. Apere rere ni Oba Olaoye je fun awon Oba miran ni gbogbo orile ede Nigeria. Olodumare aran wa lowo. Ogbomoso ko ni daru.

  • @olusholaadegoke4370
    @olusholaadegoke4370 11 ชั่วโมงที่ผ่านมา +1

    Won ki ri apeere Soun Ogbomosho fin,Oba nla ni Soun of Ogbomosho land,Soun Ogbomosho ki losi Alafin,Alafin ni wa ki Soun,but look at Oba Ghandi well respected King, well Omo Ale Ogbomosho lofa,

  • @ramotaabiolaraji1041
    @ramotaabiolaraji1041 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Kabiesi needs respect from everyone but this warning must extended to those hypocrites who hides under Kabiesi throwing stones at others.

  • @ramotaabiolaraji1041
    @ramotaabiolaraji1041 5 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    What of gbogbo enikeni who supports Kabiesi in order to discredit Imam or demonizes Islam. My advice for Sons and Daughters of Ogbomoso is to use their energy to plead to Kabiesi to be neutral in ongoing crisis. If they can do this they're truly the sons and daughters of the soil. Lagbara Olohun Ogbomoso ko ni baje. May our king lives long.

  • @helenigbarie6594
    @helenigbarie6594 11 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Good step

  • @abdullahbakọja1725
    @abdullahbakọja1725 15 ชั่วโมงที่ผ่านมา

    Good