I have said it the king is an eye service king Ogunyeye, he is not supposed for the crown, his brother is the king, he wanted to be the king so as to get many wife's, and you need money, we have a lot of minerals in yoruba land, this is what they are selling with the fulani people.
E ba wa bere lowo awon Oba oniranu leere o. Se bi Ooni Aderemi Adesoji se se niyi? A bi Ojaja ko ti daiye nigbanna ni? Se bi ti omode ko ba itan, nse lo ye ko ba aranba. Aranba sag ni Baba itan. O ye Ojaja tun wo ipebi lekan si o.
Aboriisha ni iran Yoruba. E o de ye bo Oriisha. Boya ninu isebaye,abi esin christeni. Buhari o se nkan Kan fun Yoruba,sugbon,ose mewa fun Ojaja. Iwe ti won fi nwa golu ati fadaka ni ile Osun,Buhari lo gbe le lowo. So he has every selfish rights to worship Buhari.
AWON OBA YI TI KOOLU AWON ALALE. WON TI TOWO BO SOOLO NINU IJEKUJE NINU IBAJE IJOBA NAIJIRIA.
Did Ooni of ife force the Oba Alade Ekiti to Daura? I don't think so,Yoruba Ronu.
O buru Jai. Kini imole nise pelu okunkun? Kini Oriade nwa lodo apaniyan? Omo Yoruba e kiyesara o.
O su mio
Awon oba ti awon fulaani pa ku lekiti lo ba oga awon ti o npawon