A true son/daughter of Ogbomoso will never support lies and deception. Ogbomoso people don't take nonsense. The city was founded on justice and truth. "Ogun o le ja, ja, ko ko won l'ogbomoso"
I believe this man telling the story. He never repeated his words. He is telling the truth. The arrogance of that Imam will surely bring him down for insulting the King. He has no respect for anyone.
Omo ale ni imam yen, kii se omoluabi rara. Emi igberaga si n joba ninu aye re. O n fi oba wa ni ilu Ogbomoso tayin, o n fi oba we imi idi pastor Adeboye. O n fi odidi oba ilu we imi idi, ko fi we eniyan. O ta buku oba wa. Ko ye ni ipo eniti yo ma soju Olorun labe esin Islam. Asoju Olorun gbodo je oniwa irele ati omoluabi.
Sheikh Taofik Akewugbagold and Alhaja Kaola knows the truth but they don't have the "will power" to tell the truth straight to the imposter imam's face. No lies no isilamu.
When you wonder how we became enslaved and we could not protect ourselves anymore from invaders of our beautiful land,it was because of the wicked ones among us history is repeating itself.
O ye ki won ye gbogbo satifiketi e wo ni kootu ni . Iran fulani ti won fe fi tipatipa gba ilee Yoruba ni . Won fe bere lati ori imaamu ni . Sugbon Olorun ju eda lo.
He no go better for any Imam that talk to our obas anyhow... they will all perish in yoruba land ni ase Eledumare.. awon eru larubawa mohammed won apayan
Gbogbo omo yoruba atata , , ejeki awa omo yoruba bere adura wipe gbogbo asiri gbogbo awon omo ale ile yoruba ki o bere si ni tu jade . ki asiri gbogbo won maa tu jade bayi .
E jowo e je ki won wa gbe Tani Olorun lo si Ogbomosho a ti dara ju nitoripe Ogbomosho Kii se ilu fitina,Kii se ilu awon eletan Kii se ilu awon onijibiti.,Kii se ilu awon alakatamiti, Kii se ilu awon onijagidijagan,Ilu ASA ati ise ni ,ilu ti a fi otito da ni ilu Ogbomosho Awon ti won mo owo otun won yato si osi won ni won nse akosi Ibe Tani Olorun a ngbadun e Kari goo olodumare a ti leyin
Yes, the story will be cleared & balanced if the original story of how this chief imam got there is told. Let us know why Ayilaras present him in the first place.
The Imam must be one of migrated Fulani's that have been in Yoruba Land since long time ago . I believe this is one of the signs that God have started working on Yoruba Nation actualization .
Huuunnnnn! With all said above, am sure and aware that the chief Imam still have access to the Ayilara family house in Isale-Afon, Ogbomoso. He shared government palliatives right from the family house and he often takes off from the family house in Isale-Afon to the Jumat mosque every Friday and some other days too. Well, let's wait and see as events unfold between now and December 31st this year.
Omo ale jati jati, talking to a whole king like he’s talking to omo ile-kewu. I doubt his certificates cos educated folks don’t talk like that. Eranko jati jati lori manbar in Kaola’s voice 😂
Map set of people. They lie with absolute conform, no fear of God in them at all. What a religion?! Thank God Yoruba has Itan and our itan sets record straight.
Ade ti hu Olu ni ilu Ogbomosho oooh. Chai! That Imam Toliat is a scammer. He knows he has been casted ,he now wants to cunnily turn it into a religious fight by inditing the King being a Christian
Okay Immam n je aporo ni o wa fe rough e . O fe lo social media lati fi da gbogbo e si rough. Ole ni lemaamu o fe gba ogun ologun. And he will be talking as if he already had the visa to alujanna.
Bros. I like you but always face issue and stope abusing and attacking personality of people. Well done. You are doing a wonderful work and we enjoy you everytime. Just try to be careful with the words you use.
Eranko niwon. . Awon omo ale eru larubawa oshi eru fulanis omo ale lasan lasan 😂😂oloriburuku alaye bibaje omo ale eru larubawa eru fulanis oshi omo eran lemòmu gbogbo ... alale atunbò ma tu gbogbo won lasiri danu
A true son/daughter of Ogbomoso will never support lies and deception. Ogbomoso people don't take nonsense. The city was founded on justice and truth. "Ogun o le ja, ja, ko ko won l'ogbomoso"
Ogun o le ko won logbomosho to riwipe ilu awon eso,ilu 1won jagunjagun ni Ogbomosho
I believe this man telling the story. He never repeated his words. He is telling the truth. The arrogance of that Imam will surely bring him down for insulting the King. He has no respect for anyone.
Speak your hatred out
That someone is talking without using a word for two doesn't mean he is speaking the right thing
@@Rexhamy unfortunately for you, he will pass a lie detector test in the court of law! It is called "education"
@@jamesshall5160 says by a joker. This isn't education but acute indiscipline.
Stop being a gullible Supporter
Well spoken Tani Olohun....mo gbà fun ẹ.
Awon aferu gba ibukun, asiri gbogbo won maa tu sita patapata lagbara olorun oba .
Gbogbo ohun ikọkọ lo máa wá sí gbangba, àṣẹ Èdùmàrè ni. Bí irọ bá lọ lógún ọdún, ọjọ́ kan ni òtítọ́ yíò 😢le bá 😂❤❤❤❤❤❤❤
Tani Olohun, please don't kill us here oo. You are too explicit with details. Nice one... God bless you indeed. From Houston, Texas.
Gbogbo awon alfa ati Imam wonyi make sise nice yoruba.. irumole ma ba won ja
Wo awon omo ile Ayilara bi won şe mú'ra ti won dabi Gambari-Fulani nitori ẹsin ajeeji awon larubawa
😂😂😂
🤣 😂
Awon larubawa gaan ki mura bayen awon fulani ni won mura be
Mufti omo Ale kanaa nii won awon Alakakiti esin 😮Awon omo Ale ti wa a po ni ile yoruba repete bayi oo 😮
😅😅 Love Professor Tani Olohun ❤❤
Oga ooo afi igbati omo ale je chief imam Ogbomosho
Ewe omo ni mama Tobi nta ni ilu ilogbo Eremi ni agbegbe Badagry Lagos State, I know the Imam very well at Ilogbo Eremi.
What baffles me was, ki imam ko ma leri si odidi oba! Haba!! Ikoja aiye.
Omo ale ni imam yen, kii se omoluabi rara. Emi igberaga si n joba ninu aye re. O n fi oba wa ni ilu Ogbomoso tayin, o n fi oba we imi idi pastor Adeboye. O n fi odidi oba ilu we imi idi, ko fi we eniyan. O ta buku oba wa. Ko ye ni ipo eniti yo ma soju Olorun labe esin Islam. Asoju Olorun gbodo je oniwa irele ati omoluabi.
Foolani ni most of them,they are looking to invade Yoruba land ni.
Awon Alale o ni gba fun won.
Man of the moment
My brother Taniolohun, I love you so much😢
Ta n lolohun no kill me with laughter ooooo. Mumbal 😂😂😂😂😂
Oro ogbomoso oyeki oko gbogbo wani ogbon tojasi wipe awon ipo yoruba minran awon omo ale ni odi ibemu,, sugbon oju gbogbo omo oko ile yoruba tila
Omo!...our ancestors no dey play anymore o, dem don start to dey cast all these omoale sharp sharp o.🤣🤣🤣lemomu!!! Kuro lori mombarrrrrr😂😂
Sheikh Taofik Akewugbagold and Alhaja Kaola knows the truth but they don't have the "will power" to tell the truth straight to the imposter imam's face. No lies no isilamu.
More wisdom Tani Olorun
When you wonder how we became enslaved and we could not protect ourselves anymore from invaders of our beautiful land,it was because of the wicked ones among us history is repeating itself.
Haa, oba alade ni court, eni ba foju doba, awowo aa woo
Ile ayilara tun.wa niilu saki idile oba niwon
Tani olorun e ku ohun e ku lakaye sugbon e fa fi Erin pa wa ooo
Awon oloshi olohun abatiyin nitori alejo esin
I just dey laugh ooo.... Ori monbar 😂😂
Tani olorun joor ma je ki won tun gbe e lo si ogbomosho😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅😅
Oh my God Lol
Awon ore mufti ati oba oluwo, inkan niwon je
Igbira ni mufti iwo. Awon omo alimi fe tu ile yoruba.
Ewo awon omo ile ayilara se dabi ganbari , esin musulumi di so wan di ewure onidoti .. hmmm o ma se o
Mo ti rerin yo😆🤣
😂😂😂😂😂😂 , OMO ALE FE JE ,CHIEF IMAM
💙💚💛💯
😂😂😂😂😂😂 o tun lori laya gbe Soun Ogbomoso lo si Court.
Ignoramus somebody 😂😂😂😂
O ye ki won ye gbogbo satifiketi e wo ni kootu ni . Iran fulani ti won fe fi tipatipa gba ilee Yoruba ni . Won fe bere lati ori imaamu ni . Sugbon Olorun ju eda lo.
His mum is at Ilogbo Eremi at Lagos State Badagry area, their surname is Teliat
O da mi loju pe awon Alalẹ funra wọn lo nja fun ilẹ Yoruba o, yegede oju ti young Imam omo ale, Imam ṣ'esin awọro, Yoruba nation no going back..
He no go better for any Imam that talk to our obas anyhow... they will all perish in yoruba land ni ase Eledumare.. awon eru larubawa mohammed won apayan
Foolani ni most of them,they are looking to invade Yoruba land ni.
Asiri Awon Omo ale ile Yoruba a to tu tan 😂
Gbogbo omo yoruba atata , , ejeki awa omo yoruba bere adura wipe gbogbo asiri gbogbo awon omo ale ile yoruba ki o bere si ni tu jade . ki asiri gbogbo won maa tu jade bayi .
My brother! There are some people using that imam to torment the king, they’re just playing game. You don’t need to stress yourself
Bio omode koyan Ana awon agbalagba afi itanbalefun. .... etiju niii
Lying is part of them may the Lord Almighty save us in Yoruba land
Yes o. Hijacking what belongs to them.
let start to pray that asiri gbogbo awon omo ale lori ile wa , ki asiri won ma tu sita
Well done
It's true! For ABK na imam
Opada se awon
Omo ale ni gbogbo yin
Iwo ni kolo gbe SI ewon Omo ale gbogbo ,se iro lo Pani.
E jowo e je ki won wa gbe Tani Olorun lo si Ogbomosho a ti dara ju nitoripe Ogbomosho Kii se ilu fitina,Kii se ilu awon eletan Kii se ilu awon onijibiti.,Kii se ilu awon alakatamiti, Kii se ilu awon onijagidijagan,Ilu ASA ati ise ni ,ilu ti a fi otito da ni ilu Ogbomosho
Awon ti won mo owo otun
won yato si osi won ni won nse akosi Ibe
Tani Olorun a ngbadun e Kari goo
olodumare a ti leyin
Enibafojudoba awowo awooo .....
Bomode bakoyan ale ... Afitan bale ....
When they turned slave to child ,, The child should respect elders
Eku eto ooo babá mi
Omoale ti dapo Mo oluomo
Tabi olorun please don't crack my rids oooo😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂
Good morning my brother
Kini awon idile ayilara nwo ti won je imam tele.
Yes, the story will be cleared & balanced if the original story of how this chief imam got there is told. Let us know why Ayilaras present him in the first place.
Lemomu fona gau delu Ogbomoşo ni,ao si mobi toti fonagau wa boya lati nupe or fula loti fonagau wa,ę new şalaye o.
E funwa ni ibi ti o ti bu baba soun.
The Imam must be one of migrated Fulani's that have been in Yoruba Land since long time ago . I believe this is one of the signs that God have started working on Yoruba Nation actualization .
Olosi Ni chief ogbomosho fi ori oyele kia
Set awon eru larubawa 😂😂😂
❤❤❤❤❤❤❤❤❤
Huuunnnnn! With all said above, am sure and aware that the chief Imam still have access to the Ayilara family house in Isale-Afon, Ogbomoso. He shared government palliatives right from the family house and he often takes off from the family house in Isale-Afon to the Jumat mosque every Friday and some other days too. Well, let's wait and see as events unfold between now and December 31st this year.
Thank God that Ogbomosho is not like Iwo where anything goes. Ogbomosho ò gbàgbàkugbà bí Ìwó
Isese Agbewa ooo
Ase oooooo
LET JUSTICE PREVAIL.
Why can't you people do thorough screening before His installation.. Allahu hallam
Ki won se be fun oluwo na, e ri wipe fulani ni gbogbo won
Awa Yoruba ti bęrę sini taji si awôn Islamic clerics ati awôn ôga wôn ni north şe un tôwô bô arin ilę yoruba..
Ganbari ni bobo lemomu yi. Oju e o jo oju omo Yoruba.
Foolani ni most of them,they are looking to invade Yoruba land ni.
If you meet a bastard yoruba you will know from how he talks.thats what i discover when i started listening to how the imam talks
Ninu isoro si boy na o ti fi han PE omo Fulani ni
Too many omo ale in Yoruba leadership positions and that’s why the land is suffering high level betrayals.
Omo ale ni e ti ko ba kuro ni odun yi, kini ile won un wo ti won fi we lawani fun. Mad boy eeee,
Weere gan an niwo pàápàá, se o ni etí igboro ni abi o n sun.
You are right 🙏🙏.
Olorun Oni gba fun yin eyin olote
What’s this taniolohun own?
Omo ale jati jati, talking to a whole king like he’s talking to omo ile-kewu. I doubt his certificates cos educated folks don’t talk like that. Eranko jati jati lori manbar in Kaola’s voice 😂
The imam is foolani,they are looking to invade Yoruba land ni.
@@makokin21 exactly
Map set of people. They lie with absolute conform, no fear of God in them at all. What a religion?! Thank God Yoruba has Itan and our itan sets record straight.
Gbogbo inkan ti awon ara oke oya man se niwonyi, fowo gbaju gba inkan oninkan
Imam shame dey shame mii walahiiiiiiii
Tani olorun ori ade yio gbeo ooo
Ati ko eran mero
Ade ti hu Olu ni ilu Ogbomosho oooh. Chai! That Imam Toliat is a scammer. He knows he has been casted ,he now wants to cunnily turn it into a religious fight by inditing the King being a Christian
Bọ́ọ́ lẹ̀ ń bẹ̀ ❤
Prison o kin se inkan gidi ki olorun ma se wa nin elewon eeyan o kin ti ewon de ki oro e tun normal,
Oloriburuku that how the fulani also do the there leter kill afonja, please and please etetele ku o ni ilu yin ooo
Shau 😂😂😂, ni aare musulumi ni ile Ogbomosho. Wahala wa ooo, 😢
Tani.olohun..omo.buruku.na.mo.ni.ojo.tie
What concerns you about Islam affairs now
He's from badagry
Point of correction he is not from Badagry we Badagarians knows ourselves. His mum only sell Ewe Omo at Ilogbo Eremi my home town.
How can someone be claiming what doesn’t belong to him. This is so terrible !
I wonder oooh..... Chai
Nah corruption as usual now, for this one Yoruba land.
Okay Immam n je aporo ni o wa fe rough e . O fe lo social media lati fi da gbogbo e si rough. Ole ni lemaamu o fe gba ogun ologun. And he will be talking as if he already had the visa to alujanna.
Owo face book nin Baba Alawo nfi jeun, tata toto toto Elenu Doro nun
An imposter
That Yinusa toliat is a big criminal
To ba tun gbe e losi kotu, warira re
Bros. I like you but always face issue and stope abusing and attacking personality of people.
Well done. You are doing a wonderful work and we enjoy you everytime.
Just try to be careful with the words you use.
Ki ni itumo sehu ti awon won yi npe
Eranko niwon. . Awon omo ale eru larubawa oshi eru fulanis omo ale lasan lasan 😂😂oloriburuku alaye bibaje omo ale eru larubawa eru fulanis oshi omo eran lemòmu gbogbo ... alale atunbò ma tu gbogbo won lasiri danu
I wonder o.
Alabosi Po ninu awon elesin isonu yi se. Omoale ti gba ilu Mo awa omo oko lowo Nile baba wa.
Esin
O ye ki won se ti Mufti now😂😂😂😂😂😂😂😂
Imam olojukokoro
Baba Akewugbagold suggested adoption and the people asked him if he was in that shoe would he adopted?😂😂😂😂😂
Wahala won ti poju
E beru olohun...no one will scot free if you lie. Nowadays people can proof lies with this high rate of poverty
Iwo Omo ale Omo esu lalu odaran Abdulazeez Yi. Ti Owo ba ba e oni bobe ooo
Looking at his stature, he looks more like Fulani. He is showing his certificate, who that his Certificate help😂😅😅
Isese lagba Esin
Lmao ❤❤❤
Hello do u have poultry?