CCC HYMN 276 - E BA WA YO ARA NINU KRISTI | YORUBA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 9 ก.ย. 2024
  • CCC HYMN 276 YORUBA
    1. E ba wa yo, ara ninu Kristi,
    Fun o ri rere ta ni,
    Wakati buburu na de,
    Ti o mu aiye yi gbona,
    Elese ronupiwada,
    Ni ‘jo Mimo yi.
    2. Ogbun nla si sile nisisiyi,
    Lati t’eruku jade,
    Bo ko ba fe jeni egbe,
    Si odo Olugbala Re,
    Ro mo Kristi ‘nu Ijo Mimo yi,
    Yio ran o lowo.
    3. Laipe, Baba ki yio mo omo,
    Tab’omo mo Baba re,
    K’aiye sile sa to Kristi,
    O duro loke mimo Re,
    Rukerudo ‘parun nla mbo,
    Ya ronupiwada.
    4. Mo si tun nduro ninu anu mi,
    Npe awon elese,
    Wakati yi e pawada,
    Laipe anu yio dopin,
    Fi ‘ka, aje, orisa sile,
    Kristi yio, gba wa la.
    5. Gbogbo ekun aiye ti se simi,
    Sibe nko bikita,
    Nko ro ewa ti Orun,
    Kika ni irun ori yin,
    Lomu Emi Kristi jiya na,
    Emi ni, wa, ki o ye.
    6. Niti iparun ti aiye yi,
    Mo fi anu fa se yin
    Sibe aigbagbo nposi,
    Nwon nsin orisa, aje,
    Nwon lo arakan ati ika,
    fi won le wa ‘do Mi.
    7. Mo ti pese ohun rere fun o,
    Ade didan iye na,
    Bugbe re nduro de o,
    Lori ile didara na,
    F’aiye sile, wa wa sodo mi,
    Emi o tewo gba o.
    Amin

ความคิดเห็น • 1

  • @oluwafemionayemi8372
    @oluwafemionayemi8372 หลายเดือนก่อน

    Halleluyah choir i really enjoy the songs god bless vine yard pls dont know if you can help with solfa and the song in words