OGA OO, OJU OLOYE IGBOHO TI RI OO!! EGBO ORO LENU AWON AGBA GBA!!

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 16 ต.ค. 2024
  • #babagbagedeimo #koikimedia #omoluka #tennyomoologo #trending #babagbagedelive #yeyedaratalk2 #yorubanation #aarealmoroof #trend #trending #yoruba

ความคิดเห็น • 16

  • @adetounolorundami5257
    @adetounolorundami5257 3 หลายเดือนก่อน +4

    eseun babagbadege eku aduroti wa , chief sunday igboho will surely will all the battles ijn
    lagbara olorun oba aburo gbogbo isoroeti odoju ko 😊

  • @philipodofin2457
    @philipodofin2457 3 หลายเดือนก่อน +4

    Yoruba ti se tan lati lo. Yoruba nation no going back

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 3 หลายเดือนก่อน +2

    Yoruba nation no going back , yoruba natoin lafe .

  • @MabaayomijeAmisu
    @MabaayomijeAmisu 3 หลายเดือนก่อน

    Yoruba Nation a se oju emi gbogbo wa, Sunday Igboho, Baba Akintoye, ati gbogbo awon sorosoro, Yoruba Nation a wa si imuse, ama je Oro ree Amin Jesu
    Yoruba Nation no going back

  • @OyeyemiSalau
    @OyeyemiSalau 3 หลายเดือนก่อน

    Edupe lowo Gbogbo awon asoju yoruba
    Awon alale ti gba ile yoruba funwa
    Yoruba nation ni ona abayo
    Yoruba nation no going back

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 3 หลายเดือนก่อน +1

    Konire gbogbo yin loruko jesu baba Akintoye ati sunday adeyemo igboho oosa olorun onifi gbogbo yin sile loruko jrsu ekusr ilu .

  • @mathewogunsola5835
    @mathewogunsola5835 3 หลายเดือนก่อน +2

    The blood of those people being killed by Nigeria DSS in the house of chief Sunday Adeniyi Adeyemo on July 1st 2021 will cry for revenge from those DSS and their accomplacee

  • @josephmorenike2153
    @josephmorenike2153 3 หลายเดือนก่อน +3

    Olooto ki leni,Ole ole alagabangebe lo nleni leyin. Sugbon atubotan won KO Ni dara

  • @mathewogunsola5835
    @mathewogunsola5835 3 หลายเดือนก่อน +1

    Baba wa Sunday Adeniyi omo Adeyemo, ooni ku, ooni run, wa bori gbogbo awon ota re nile, loko ati nibi gbogbo, oju ma ti gbogbo awon ota ile Yoruba, ati awon omo ale ile Yoruba ti o nwa ipalara fun Sunday omo Adeyemo, gbogbo awon DSS ile Yoruba ti jakule, won mofo, won ti padanu ayeraye, nwon ti kabamo ise ibi ti won lo se nile baba wa oloye Sunday Adeniyi omo Adeyemo ni ojo kini osu keje odun 2021. Gbogbo awon ti o kowo rin lo si ile Sunday Adeyemo omo Adeniyi patapata ma foju sunkun omo, aya ati molebi won, ayafi ti Sunday Adeniyi omo Adeyemo ba se yin, bi beko igbe ekun rara ko ni tan ninu ile enyin asebi wonyi lagbara Oluwa Olorun ti o da aiye ati orun

  • @YemiOdejobi
    @YemiOdejobi 3 หลายเดือนก่อน

    Our Savior Chief Dr Sunday Adeniyi Adeyemo Angeli ti a, Eni Ami Ororo Oluwa: Eyinju Olorun Baba-wa; Olodumare
    Apa otakan kiyo ka o lagbara Olodumare Ire, Ire, Ire Ayo, Itunnu ati Alaafia laomari IJMN Ase 🙏

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 3 หลายเดือนก่อน +2

    E ku ise takuntakun

  • @Segunshow1996
    @Segunshow1996 3 หลายเดือนก่อน +7

    Nigeria is not good for we Yoruba people we have to exit out of Nigeria
    Yoruba nation no going back

  • @SerahGibson
    @SerahGibson 3 หลายเดือนก่อน +1

    GBOGBO OMO YORUBA ATATA, LAKOKO MO GBADURA FUN BABA, BANJI AKINTOYE,OJU KI YIO TI NYIN, EO PONWA JINNA OLUWA YIO DA EMI SI, LATI KO GBOGBO AWON OMO NYIN DELE ILERI NWON.WAYIO MO WA FI TOWOTOWO DUPE LOWO OLORUN, LORI EGUN NLA TI GBEHIN IGBALE. SUNDAY ADISA ADEYEMO, OMO ALADIKUN. TORIPE ADE ALADIKUN ON LA GBA FUN ALAFIN.OMO LADE, LADE, NLADE. YIO YE O,YIO DARA FUN O, NI GBOGBO ONA NI AGBARA OLORUN. OKU ISE, ISE NA KONI DISE MO E LOWO ADISA, PELU ASE TI OLORUN FI DA AIYE ON ORUN, DANDAN NI TI AIDAN WA DE ILE ILERI NA, AWON ALALE ILE KOOTU OJIRE, YIO SE ALATILEHIN FUN O, IKUNLE ABIYAMO KONI JEKI O SUBU FUN OTA YO, ASE GUN, KOYIPADA, NI ASE ORUKO BABA WA, ELEDUMARE OBA WA, AIKU, AISA,AIDIBAJE, WIBE SEBE OLODUMARE OBA AIYERAIYE. OBA KANRINKESE, OKANSOSO NINU ORUN, AIYE,ATI OHUN GBOGBO TI OWA NINU RE, ADISA. MO GBADURA FUN O PE, EMI RE YIO GUN OMO KONI KU, BENI AWON IYAWO KONI KU MO E LORI. IWO TIKALARA RE KONI SEKU, BENI ATEPE LESE NTENA GBOINGBOIN LOKE, WA PE LOKE EEPE. ASE GUN. GBOGBO WA PATA OMO KOOTU OJIRE
    OLUWA YIO FI AANU DAWA LOHUN KIAKIA, YIO SI SOJU EMI WA. GBOGBO WA NI AO PEJU WA NIBE, NIGBATI A BA NA ASIA NA SOKE. AO NI FOMO SE ATI ARA WA, OKUNRIN, OBINRIN, OMODE,AGBA,ASE IDI, OMO IRINSE, ATI OMO OMU, GBOGBO WA NI AO PEJU WA NIBE, NI AGBARA OLORUN OBA TI O DA ORUN ON AIYE
    OTIRIBE AND LASE ELEDUMARE OBA. ASE WA.NI ORUKO JESU OLUWA WA ATI ALUBATA WA. AMIN ATI ASE. AMIN LORUKO JESU OLUWA WA. AMIN. AJUWASE O.ASE.

    • @mathewogunsola5835
      @mathewogunsola5835 3 หลายเดือนก่อน

      Aaamiiin lOruko Jesu Kristi Oluwa wa

  • @AdeboyeMayungbe
    @AdeboyeMayungbe 3 หลายเดือนก่อน

    Why all these terrible and bad treatments against the Yorubas in our fathers land. Incredible !!!!!