BAYOWA GBENGA ADEWUSI / ADEBAYO FALETI / AKONI OMO OODUA

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 18 ต.ค. 2024

ความคิดเห็น • 41

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  7 ปีที่แล้ว +5

    Emó kú ojú -òpó dí, Àfèèbòjò kú enu isà dìkàsì. Adébáyò Fálétí lo náà nu! Alágbède ìjìnlè èdè Yorùbá lo nílè yì í tèfètèfè! Òpómúléró àsà lo àbùsé bùse. Dídún ni Dùndún ń dún Dídùn ni ìrántí olódodo! Wón rò pé wèrè ni, wèrè kó, Ìdààmú Páàdì kò já sí pàbó sùgbón o se fere bí Ekùn o fò lo! Fálétí lo bí oyin se e sí lo ni kókó igi, Adébáyò pèyìndà bí ìgbà tí òkàsà bá lo lalè odò! Gbogbo pèdèpèdè nílè yì í, e kú ìdárò eniire! Èdùmàrè kò ní se é ní àkúfà! Òrun dèdè má ì kánjú gbogbo wa là ń bò pèsèpèsè!

  • @bolatitoesther9796
    @bolatitoesther9796 7 ปีที่แล้ว +4

    Akoni looo,omo. Yoruba atata,eni bi baba ADEBAYO shon won ni ile Nigeria ati ni ile Yoruba ,Baba ki soro sa tabi da si oroti ko wulo .Erin wo Erin koledide mo ipàde di oju ala odi gbere,

  • @ajokkybabeoduntan2080
    @ajokkybabeoduntan2080 7 ปีที่แล้ว +3

    the great man....May him soul rest in perfect peace. ..sun re ooo baba adebayo

  • @ceoglobalanalytics5620
    @ceoglobalanalytics5620 2 ปีที่แล้ว

    i so love this man. the greatest. baba fi yooba wu'yan

  • @solomonesthersolomomesther2707
    @solomonesthersolomomesther2707 7 ปีที่แล้ว +6

    Rest in peace BABA,we love u but GOD love u most,Gbogbo Omo Yoruba,aku idele baba wa

  • @naija4lifeNaija4lifestyle
    @naija4lifeNaija4lifestyle 7 ปีที่แล้ว +2

    RIP! Long live the Yoruba Culture and tradition! !!
    Thanks for sharing!

  • @imantv7237
    @imantv7237 7 ปีที่แล้ว +3

    Hummm erin subu kole dide
    Oma se ooo RIP baba faleti

  • @adedayofatoki8345
    @adedayofatoki8345 7 ปีที่แล้ว +4

    My first encounter with baba was through his book "Bashorun Gaa", in 1986/87. We thank God for his life, a life well spent in the service of humanity. Rest in Peace, Baba.

    • @mojisoladeji
      @mojisoladeji 7 ปีที่แล้ว

      I need to get that book...

  • @obaomoadunky232
    @obaomoadunky232 7 ปีที่แล้ว +4

    Gbogbo awa omo yoruba a ku ara fe ara ku ti baba wa Adebayo Falati omo Oyo alafin ojo pa sekere omo atiba ki Olohun fi ori jin won,ki Olohun duro ti Awon iyawo ati Omo ati omo'omo baba wa

  • @taiwoakande2196
    @taiwoakande2196 7 ปีที่แล้ว +3

    I love this man. May his soul rest in peace.

  • @mojisoladeji
    @mojisoladeji 7 ปีที่แล้ว +1

    I don't understand why anybody will dislike this video. Some people sha....

  • @ajokkybabeoduntan2080
    @ajokkybabeoduntan2080 7 ปีที่แล้ว +1

    The great man. ...May him soul rest in perfect peace. baba Sun re ooo

  • @Babatundey
    @Babatundey 7 ปีที่แล้ว

    What a BIG LOSS 💔... Once in a lifetime ICON 💚... Rest In Peace Sir 🙏🏾

  • @jeebsola9168
    @jeebsola9168 7 ปีที่แล้ว +2

    Aww! So sad. May his soul rest in peace. Love you baba dada

  • @oyedokunfolashade3045
    @oyedokunfolashade3045 7 ปีที่แล้ว +1

    Baba Adebayo Faleti Orun re re o .Rest in peace baba

  • @euniceowolabi4831
    @euniceowolabi4831 7 ปีที่แล้ว +2

    He Was a great and lovely man.

  • @dayoofere8513
    @dayoofere8513 7 ปีที่แล้ว +2

    May Papa Soul Rest in Perfect Peace

  • @infoolakunmi907
    @infoolakunmi907 2 ปีที่แล้ว

    Please sir, upload thunder nite by muri thunder

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  7 ปีที่แล้ว

    ADIEU GIWA EDE ATI ASA YORUBA

  • @dayoofere8513
    @dayoofere8513 7 ปีที่แล้ว +2

    Wish to see that movie Asewo toh re Mecca

  • @boseidowu4565
    @boseidowu4565 7 ปีที่แล้ว +1

    May his perfect soul rest in peace . Ameen

  • @teepeealonzo1871
    @teepeealonzo1871 7 ปีที่แล้ว +2

    continue to rest in peace baba.

  • @oladeleoluwaseun3427
    @oladeleoluwaseun3427 7 ปีที่แล้ว +3

    may him souls rest in bossomo of lord

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  7 ปีที่แล้ว +1

    Thank you all

  • @dayoogunleye6073
    @dayoogunleye6073 7 ปีที่แล้ว +1

    Baba rest in perfect peace.

  • @oyelayojoshua1239
    @oyelayojoshua1239 7 ปีที่แล้ว +1

    R.I.P Baba rere.

  • @murainaoyelami6858
    @murainaoyelami6858 7 ปีที่แล้ว

    I ba se p'aiku, Ara a gbahun da?

  • @zacchaeus4514
    @zacchaeus4514 ปีที่แล้ว

    Ede ati asa Yoruba wuyi pupo.

  • @olamother2608
    @olamother2608 7 ปีที่แล้ว +1

    may ur soul rest in peace baba

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  7 ปีที่แล้ว

    Keep watching YorubaSwagaTV on TH-cam for the best Movies, Musical Videos and Unlimited Entertainment. Swaga ni joooooo

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  7 ปีที่แล้ว +2

    Keep Watching YorubaSwagaTV on TH-cam 4 D Best Movies & Musical Videos

  • @bunmiadeyinka8152
    @bunmiadeyinka8152 4 ปีที่แล้ว

    Rest in peace baba

  • @funmilolaakintunde309
    @funmilolaakintunde309 7 ปีที่แล้ว +1

    r.i.p baba

  • @YorubaSwagaTV
    @YorubaSwagaTV  6 ปีที่แล้ว

    I'm simply GBENGA ADEWUSI. Hello my good people and Caring friends. Let's SWAGGER together for good @ NIGERIAN ARTS, FASHION & BEAUTY (NAFB) AWARDS 2018 in HOUSTON TEXAS. I'm coming for real.
    Date: Saturday, May 5. Time: 6:00pm.
    Venue: HILTON HOUSTON GALLERIA HOTEL. 6780 SOUTHWEST FREEWAY, HOUSTON, TEXAS 77074. Dress code: STRICTLY

  • @ogunlowowasiu1856
    @ogunlowowasiu1856 7 ปีที่แล้ว

    my kids and i

  • @waheedadebola7077
    @waheedadebola7077 7 ปีที่แล้ว

    RIP

  • @dayoogunleye6073
    @dayoogunleye6073 7 ปีที่แล้ว +1

    Baba rest in perfect peace.

  • @lizzyjoledo5441
    @lizzyjoledo5441 7 ปีที่แล้ว +1

    RIP

    • @adebayokehinde3100
      @adebayokehinde3100 7 ปีที่แล้ว +1

      katori Erin odi igbo katori Eton odi odan katori iru baba mi faleti iyoku Ku so odo olodumare oba aterere kari aye itori iru olodumare ni kosi,babami faleti majokun maje ekolo hun to won ba nje ni ajule orun ni kilo mo ba won je orun re re hooo