Bisimillahi Rahman Roheem Oba to fun mi ni ibere itan yi gbo Dakun fun mi ni ipari itan yi gbo Ki itan na wa lapa ni Ara mi Ki olohun wa bami bun olusotan wa ni Emigigun Ati Alafia to peye Ameena Ya Allah
Iwa ti koye ki oba obinrin de ile oko lowa lowo Adenike,lati igba ti Ajao ni ri iwa yi to ti nba so ti ko gbo loye koti te siwaju ninu irin ajo e sugbon nigba miran opo awa odo aman foju fo awon iwa kookan lasiko ti aba nrin irin ajo ife wa ti osi le fa ipa lara fun ibasepo wa toba ya
Bisimillahi Rahman Roheem
Oba to fun mi ni ibere itan yi gbo
Dakun fun mi ni ipari itan yi gbo
Ki itan na wa lapa ni Ara mi
Ki olohun wa bami bun olusotan wa ni Emigigun Ati Alafia to peye Ameena Ya Allah
Ese olotu ❤❤❤
God bless you sir
Oni gberaga ni adenike
Ifarada lole ko aye ja ....aku ibere ishe tutu ao gounle ayo lase Allah...
❤❤❤❤❤🎉🎉🎉🎉🎉
❤❤❤
❤❤❤❤❤❤❤
Humm o ga ooo
Thank you sir, may Allah continue to strengthen you.
Eku ise opolo sir, olohun ama wa pelu yin sir
Thanks so much God bless you
If Ajao intention is to marry this lady,this is a RED flag.
Just to be a casual friend
.E ku ise oo
Thanks so much sir
Life principle would be compromise no doubt
Thanks sir
Eeyan kan ki i gbon tan. Ogbon ologbon ki i je ka pe agba ni were.
Yoo da ra fun yin o
Iwa ti koye ki oba obinrin de ile oko lowa lowo Adenike,lati igba ti Ajao ni ri iwa yi to ti nba so ti ko gbo loye koti te siwaju ninu irin ajo e sugbon nigba miran opo awa odo aman foju fo awon iwa kookan lasiko ti aba nrin irin ajo ife wa ti osi le fa ipa lara fun ibasepo wa toba ya
Anike ko mo wipe eko laisi iwa irele ofo ojo keji oja ni.
E seun pupo sir.
Adenike feni igberaga die❤❤❤❤
Eku ise o olorun yio ma ti yin leyin
Thanks ❤❤
God already show mr Ajao that this kind miss Adenike is not good wife, but some time because of love we over look it but in marriage bug problem
😂😂😂😂😂😂
Anike ni lati farabale gbo nkan ti ajao ba so