IRU AWỌN AṢOFIN WO LO WA NI NAIJIRIA YII NITORI ỌLỌRUN.

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 11 ก.ย. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

ความคิดเห็น • 35

  • @adeyemiyusuff6458
    @adeyemiyusuff6458 22 วันที่ผ่านมา +2

    Mama Alaroye you are too good ❤❤❤❤❤❤❤

  • @classyjoyce5452
    @classyjoyce5452 23 วันที่ผ่านมา +2

    God almighty will continue to bless you ma for saying the truth

  • @beejay6963
    @beejay6963 22 วันที่ผ่านมา

    Sister mi Olohun iyo, E ku ise takuntakun, Eledumre a maa fun yin se❤❤❤❤❤

  • @ABDULKARIMSALMAN-d5m
    @ABDULKARIMSALMAN-d5m 23 วันที่ผ่านมา +2

    ❤ Alaroye eku ise takuntakun Adupe o ti e je ki eti wa di si Ohun to nlo lawujo wa,Bawo ni orilede se fe ni ilosiwaju, Edumare gbawa ooooo❤

  • @user-xn6kn6eg6q
    @user-xn6kn6eg6q 23 วันที่ผ่านมา +2

    Àhh 😳 olorun oooo
    Awon apanilelun jaye sinato olorun a mu gbogbo yin lagbara olorun AMIN

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu9017 22 วันที่ผ่านมา +2

    Oloriburuku ni Awon asejoba kilode Olorun koshanu wa Amin Huuuum Amon sha Gbogbo won ni won kiku Esan lagbara Olorun iyenbe
    Obasanjo gan fun ara AJALA talona sebi IWO Nani Olorun Amuyin ati Tinubu ati Obasanjo ati Buhari Jonathan Gbogbo OLÉ OFON olowo mewa niwon GOD Blessed YORUBA LANDS First 🙏🏿 Iya Alaroye KUDOS 👍🏿

  • @haynehifanny8006
    @haynehifanny8006 23 วันที่ผ่านมา +2

    Awọn aṣofin olè, ojẹlu, onijibiti, alainitiju, ọlọṣa, Ọlọrun ma pa gbogbo wọn ni ipakupa ni.

  • @lukmonolamilekan8616
    @lukmonolamilekan8616 22 วันที่ผ่านมา

    Haaaaaaa 🏧🙆🏼🙆🏼🙆🏼 nitori olohun tanio wa gbawa bayi olohun oooooo😢😢😢

  • @alicewilson4836
    @alicewilson4836 23 วันที่ผ่านมา +1

    ❤❤❤❤

  • @LukmanAgbaje
    @LukmanAgbaje 23 วันที่ผ่านมา +2

    Hmmmmm Nigeria 🤔🤔🤔🤔

  • @OmoleckJames-wz7od
    @OmoleckJames-wz7od 22 วันที่ผ่านมา

    Elonisuru, asikotidetan, awon olojelurun yii ni yio mabere sii parawon, idinipe, wonmope, awontigungikojaewee, awon alejokanbo lati orileede ajeji, tiyiowamaabawonja gidigidi, owo owo wonyen koniwulofunwon

  • @AkinloluJelili
    @AkinloluJelili 23 วันที่ผ่านมา +1

    Onijekuje Nigeria o ga ooo

  • @monisolarahman762
    @monisolarahman762 23 วันที่ผ่านมา +1

    Alaroye naa wa lara isoro awa Omo Yoruba, pelu ogbon imo ati oye Omo Odo agba, koye ki won ri wipe Nigeria ti jona, sugbon ojo nbo ti were ma lu eniti o nwosan pa, ire o 😂😂😂

  • @comfortadeoye5748
    @comfortadeoye5748 23 วันที่ผ่านมา

    Ohun taa nso niyan pe ka pin,yoruba nation ni ona abayo Kaluku yoo se Tara re

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 22 วันที่ผ่านมา

    Hmmmm
    Oro Nigeria kojo awa loju

  • @sakenatafolabi8666
    @sakenatafolabi8666 23 วันที่ผ่านมา +1

    HMMMMMMMMM NIGERIA 🤔🤔🤔😭

  • @olubayoelegbede7963
    @olubayoelegbede7963 23 วันที่ผ่านมา

    Yoruba nation is here to stay

  • @vincentolabisi8298
    @vincentolabisi8298 23 วันที่ผ่านมา +1

    Ki gbogbo omo Nigeria dide bere eto won lati igbati baba oba ti nse ijoba. Ki a gba ile ati moto won lowo awon oniselu gbogbo. Révolution is ready..

  • @fatalkehinderaheemat1513
    @fatalkehinderaheemat1513 22 วันที่ผ่านมา +1

    Sebi won ti so gbogbo omo Nigeria di oni gbese tan

  • @hardenikeoluwaseun8408
    @hardenikeoluwaseun8408 23 วันที่ผ่านมา +1

    Awon Ole ni senito won yii o

  • @bukolaadeyemiawayewaserere1313
    @bukolaadeyemiawayewaserere1313 23 วันที่ผ่านมา

    Ę ku ise takuntakun 🎉

  • @BisiriyuoOwolabi-mc4ox
    @BisiriyuoOwolabi-mc4ox 23 วันที่ผ่านมา +1

    Ile igbimo asofin ati asijusofun gann no Agba isoro Nigeria. Ibinu Olohun ni ibuso won

  • @adeyemoademolajammy2002
    @adeyemoademolajammy2002 22 วันที่ผ่านมา +1

    Ilu ti awon oloriburuku ti baje already.

  • @JuliaBrame-e2l
    @JuliaBrame-e2l 22 วันที่ผ่านมา

    Rodriguez Elizabeth Moore Jennifer Johnson Dorothy

  • @sussanahogunbo6681
    @sussanahogunbo6681 23 วันที่ผ่านมา +1

    ELEYI MA WA GA O IYA ALAROYE ORIN KINI KA KO SI EYI AFI KI OLORUN KO WA YO O TOJU SU GBOGBO WA O ORI GBOGBO WA YIO DA WON LEJO LAGBARA OLORUN

  • @AdemolaShittu-iu7Ct
    @AdemolaShittu-iu7Ct 17 วันที่ผ่านมา

    Baba obasanjo ti setsn lati tun ilu se Sugbon o taa ko to o won da oputa panel sile ko ro ofin lagbara lati muwon timole won pada sodi imuniti mo lowo

  • @OlufunkeFajimolu
    @OlufunkeFajimolu 19 วันที่ผ่านมา

    Ika ni gbogbo won, no more allowances for them,the same people get #160m cars 4rm Tinubu when they are all corrupt cabinets,no water, no security, no good roads, no education, no hospital, no food.

  • @user-jk2xg6hb1n
    @user-jk2xg6hb1n 22 วันที่ผ่านมา

    Ibereminkinodetiawoneniyankilesorotiwannipotiopetiwonsinimonniwanmontuasirielomintiobagbaijoba

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 23 วันที่ผ่านมา

    Talo nfowosi (sign) iru owo buruku bayi fun sisan funwon ? Sebi won kole da gba iru owo buruku bayi lososu funra won lalai je wipe lati oke wa ni wonti fowo si (sign) sisan

  • @pauloladimeji2514
    @pauloladimeji2514 23 วันที่ผ่านมา

    Tinubu ni gbogbo yin maa npariwo, se e ni alaafia sha?
    Tinubu to sese de, tomba oro Aje ati gbese toba Nile ja lowo, Koda oro aabo koje ko le sun, etun wa npariwo, Tinubu ko lo ge owo awon Ashofin.
    Se gbogbo yin kosi laye, nigbati Obasanjo da wahala yi sile, lati local govt titi de Senate.
    Oni ki oselu ba le fese mule ni.
    Okanjuwa, wa ndagba ogbon nrewaju si.
    Oju gbogbo yin ni Obasanjo ati Atiku se ya Billion dollars lati se Ina fun Naijiria, sugbon toje pe nse niwon pin mo ara won lowo, ati bee , ati bee bee lo.
    Oju yin ko fo nigba naa, sugbon Obasanjo naa lowa nsoro biipe eeysn gidi niwon bayi.
    Tiee batile so oju Abe niko, ki e so ooto fun awon Toda wahala yi sile, nise ni ki edake enu yin, ki e ye fete sile maa pa lapalapa.

    • @MaryAlex-sp7yz
      @MaryAlex-sp7yz 22 วันที่ผ่านมา

      Oga shut up

    • @pauloladimeji2514
      @pauloladimeji2514 21 วันที่ผ่านมา

      @MaryAlex-sp7yz Go and shut your papa up @ home. Senseless, bastard.

    • @pauloladimeji2514
      @pauloladimeji2514 21 วันที่ผ่านมา

      ​@@MaryAlex-sp7yz Go and shut your Papa up.
      Nasty idiots.