Abosi wa po ni Ipinle Ogun. Ko si kini kan kan ti won se ni iranti Sodeke. Gomina Ipinle Ogun ana ati awon mii nso oruko awon ibikan loruko, Ewang (ajeji ti o ti je Gomina ri) ,, Ewang Estate ati Muhammadu Buhari Estate ni Oke -Mosan, ati Ibrahim Babangida Boulevard ni ilu Abeokuta. Won o si se kini kan ni iranti Akoni Sodeke. O ti ni loju pupo. Omo Egba Oke-Ona lemi , awon obi mi mejeji.
Nice research work...keep it up sir. For long I have known that the Yoruba race are far older than the Oduduwa age. Oduduwa age is that of a new era/civilisation.
Thank you for your excellent, picturesque delivery of our history - the Yoruba history! Advice: You may consider muting your electronic device(s) during recording to avoid the occasional beeping. Thank you.
Sodeke is a super warrior we in Remo already known that for a very long time. YORUBA is in big trouble, I think YORUBA as a race are suffering from big curse.
Ah.. Mo ṣẹ̀ṣẹ̀ ń rí eléyìi ni.. Ojú sì ń tì mí... Ọmọ Ẹ̀gbá ni mí... Òkè-Ọnà, .. Agbo ilé wa wà ní ìtòsi Olúmọ.
You are great for Yoruba Yoruba History
Proudly from Egba born in Lagos ,Ẹ̀gbá ọmọ lisabi👍
Laji Abbas Eku Ise opolo anfara bale lati gbo oro yi Ara OWU won kiira ranro awi menukuro ni tii OWU kare laji Olorun amafun yin se ASE
Grandson of Sodeke from United states of America greets and praises you.
Same here my brother 👊❤
1a÷r666
Abosi wa po ni Ipinle Ogun. Ko si kini kan kan ti won se ni iranti Sodeke. Gomina Ipinle Ogun ana ati awon mii nso oruko awon ibikan loruko, Ewang (ajeji ti o ti je Gomina ri) ,, Ewang Estate ati Muhammadu Buhari Estate ni Oke -Mosan, ati Ibrahim Babangida Boulevard ni ilu Abeokuta. Won o si se kini kan ni iranti Akoni Sodeke. O ti ni loju pupo. Omo Egba Oke-Ona lemi , awon obi mi mejeji.
Proudly Egba, proudly daughter of Sodeke. Thank you.
Good talk laji Abbas God bless you 🙏
Eku ise opolo are opin itan. Oriyin. Koniburu. Amin
Good job. May the Almighty God continually enrich your knowledge.
May Almighty Allah bless you and your generation
Sodeke is a great warrior according to the oral traditions and history of Yoruba land.
Iba Olodumare, iba YORUBA
Nice research work...keep it up sir. For long I have known that the Yoruba race are far older than the Oduduwa age. Oduduwa age is that of a new era/civilisation.
Thank you for your excellent, picturesque delivery of our history - the Yoruba history!
Advice: You may consider muting your electronic device(s) during recording to avoid the occasional beeping. Thank you.
Sodeke is a super warrior we in Remo already known that for a very long time.
YORUBA is in big trouble, I think YORUBA as a race are suffering from big curse.
Ẹ má kọ ọ̀rọ̀ yín ní èdè Yorùbá
Alafin.Aole curse is still working on Yoruba race
good work
Ìpóró, Ijẹmọ̀, Ìtòkú, Ìtokò, Èrunwọ̀n..
Oluko Agba, asiwaju ninu oluwadi ijinle ti asiko yi
Lisabi Egba
Eku ise opolo Aare. Sugbon e o pe awon oruko Oruko awon ilu kan daada.
Tí a bá rí orórì Ìyálóde Tinubu ni Àgọ̀ Òdo, ojú á gbà wá tì.
The burial ground of Ìyálóde Tinubu in Abẹ́òkúta is abandoned.
"Makama" yen dabi oruko awon Borno tabi awon beri-beri. O se bi eni to ru mi loju die.. Ko jo bi oruko Yoruba leti mi.
Aku aseku odun oluko agba
Olorun ama so agbara di otun
This is deep!!!
Eku eto
Owode
Are please always use your normal voice, you don't need to emulate movie narrators. Please