Pavilion, you are funny interestingly. Bo ba bo sokoto tinnrin wa wonan, to ba fonu fodi wa wonan, to ba seleyi seleyi wa wonan, taani danan ninu yin? I love you Pavilion over your strategical presentation
Great news ! God make our leaders speak the truth on our behalf. Silence and indifference is sickening. Kudos to Gani Adams, to governors of Oyo, Ekiti and Ogun. Let us hear more courageous voices of Yoruba leaders to speak out for Yoruba people.
Baba Pavilion! Kosi lowo eniti oje amala tiko siwo, eniti ofi egusi se nanmon ni ko se un. Nigbati awon omo ale ile Yoruba ti nfi awon Ahusa joye ninu Aafin ni ile Yoruba, nigbati won ti npe won lati oke oya kiwon wa si masalasi ni lbadan, nigbati oje wipe awa Yoruba koda osupa ati irawo mon ni oju orun, odi igbati awon afoju ba so fun wa, sibe sibe awon ara ibi kofe ki ashamun ati itunu aawe dawa po. Aisan wa ni ara opolopo awa omo Yoruba, ajegbodo nwa eni kunra ni awon eniyan wa. Won fe ko oriburuku tiwon ranwa, kole sese, olori buruku yen so wipe tiwon koba gba enanwon, erin re sipa mi gidigidi.
They are taking noticed, of the way we are agitating for Yoruba nation, and that it might be possible that Yoruba nation be reinstated and b4 that, they would deceitfully launch Sharia in Yoruba land in order to seize the opportunity to annex our land. Yorubas should rise to resist the ugly plan. Yoruba nation is our mission and vision to achieve this year, may God bless Yoruba nation.
Let Sokoto emir keeps his sharia laws into his own pocket because Yoruba is very far to Sokoto. Therefore he should hold his peace for ever if he doesn’t want GOD to gives him work to go and be counting the sand beside the sea for his remaining of his life.
God bless Yoruba Nation Now and Always
Pavilion, you are funny interestingly. Bo ba bo sokoto tinnrin wa wonan, to ba fonu fodi wa wonan, to ba seleyi seleyi wa wonan, taani danan ninu yin? I love you Pavilion over your strategical presentation
Olorun o ni gba fun won ,alaisooto ni won ajegudujera ni won yoruba ti duro yoruba nation no going back
Great news ! God make our leaders speak the truth on our behalf. Silence and indifference is sickening. Kudos to Gani Adams, to governors of Oyo, Ekiti and Ogun. Let us hear more courageous voices of Yoruba leaders to speak out for Yoruba people.
Yoruba Nation No Going Back
Since the start of indiscriminate killings in Southwest Nigeria, the Sultan never condemned it. Why is he pushing for Fulani Agenda now?
Yoruba Nation is the only way to this problem
Baba Pavilion!
Kosi lowo eniti oje amala tiko siwo, eniti ofi egusi se nanmon ni ko se un.
Nigbati awon omo ale ile Yoruba ti nfi awon Ahusa joye ninu Aafin ni ile Yoruba, nigbati won ti npe won lati oke oya kiwon wa si masalasi ni lbadan, nigbati oje wipe awa Yoruba koda osupa ati irawo mon ni oju orun, odi igbati awon afoju ba so fun wa, sibe sibe awon ara ibi kofe ki ashamun ati itunu aawe dawa po.
Aisan wa ni ara opolopo awa omo Yoruba, ajegbodo nwa eni kunra ni awon eniyan wa.
Won fe ko oriburuku tiwon ranwa, kole sese, olori buruku yen so wipe tiwon koba gba enanwon, erin re sipa mi gidigidi.
They are taking noticed, of the way we are agitating for Yoruba nation, and that it might be possible that Yoruba nation be reinstated and b4 that, they would deceitfully launch Sharia in Yoruba land in order to seize the opportunity to annex our land. Yorubas should rise to resist the ugly plan. Yoruba nation is our mission and vision to achieve this year, may God bless Yoruba nation.
Oluwo nda ile Yoruba ru ! To ba je looto Aregbesola lo mu Rasidi sile, Are gbe ni ka bawi Lori ile Yoruba to ndaru bayi.
The Kabiyesi Ewi of Ado and the Gov .of Ekiti have declared that' there is no chance for Sharia in Ekiti
Let Sokoto emir keeps his sharia laws into his own pocket because Yoruba is very far to Sokoto. Therefore he should hold his peace for ever if he doesn’t want GOD to gives him work to go and be counting the sand beside the sea for his remaining of his life.
E je ki emir Sokoto toku Sharia re si abe sokoto re. Sokoto Nina si ILE YORUBA .
Oba fi seriki joye laarin asiko ti Fulani ti le awon eeyan re kuro ni lmeko, o yani lenu gidigidi
Iru oba wo lo n fe Fulani oloorun? Boya iru oba beeee nan ko si iyato laarin won.