OONI ILÉ IFẸ̀ LỌ ṢE IDUPE NÍLÉ ÌJỌSÌN PẸLU ỌMỌ RẸ TADENIKAWO

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 23 ธ.ค. 2024

ความคิดเห็น • 21

  • @KudiratBailey
    @KudiratBailey หลายเดือนก่อน +3

    Congratulations to our Kabiesi and queen Naomi❤❤❤

  • @AYEKOOTOTV812
    @AYEKOOTOTV812 หลายเดือนก่อน +3

    Congratulations baba Ooni Yoruba nation la fẹ o

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 หลายเดือนก่อน +3

    Yoruba Nation la fe

  • @princeayo9513
    @princeayo9513 หลายเดือนก่อน +2

    Baba wa Ooni, orileede Yoruba nikan lole funwa laye lati te siwaju oooo. O better ki e tete darapo pelu professor Banji Akintoye ati chief Sunday Adeyemo Igboho Oosa lati kuro ninu location apanilekunjaye liegeria ki o to dive ori itę yin di ti emir gegebi ti ilorin. The earlier the better for us koto pęju

  • @olusanyaramota1591
    @olusanyaramota1591 หลายเดือนก่อน +1

    Congratulations oba oni of ife

  • @GBADEBOGBADEGESIN22
    @GBADEBOGBADEGESIN22 หลายเดือนก่อน +3

    Ẹ joo Orile Ede Yoruba no going back

    • @helenahmed9189
      @helenahmed9189 หลายเดือนก่อน

      Nigbawi ni won bere si n gba ki won de fila tabi ade ninu church ni Nigeria. Jesus ni Oba awon oba, nitorina ni owo ati ola se fi fun Jesu pelu yiyo fila ninu Church. But the Jewish Priest wear head cover by the prescription of the robe God told Moses they make for High Priest.Adura o ma n gba ninu irele okan ati bi bu Owo fun Oluwa Eleda wa. Olorun ti oni emi wa ati akoko wa ninu aye Yi.

  • @beckybeautyworldshow
    @beckybeautyworldshow หลายเดือนก่อน +3

    Yoruba nation no going back

  • @NETWORKTVSHOW22
    @NETWORKTVSHOW22 หลายเดือนก่อน +2

    Orile Ede Yoruba nìkan ṣoṣo lona abayo enough is enough

  • @olusegunbabajide1509
    @olusegunbabajide1509 หลายเดือนก่อน +3

    TADENIKAWO is a carbon copy of Kabiyesi OniOrisha Ojaja the 2nd 🙂

  • @OmoleckJames-wz7od
    @OmoleckJames-wz7od หลายเดือนก่อน +1

    Oba, ashiwaju awon ojeun epe Santa, oba, Eyin tenfiyajewa ni Yoruba Olorun yiofiyajeyin, owo tiegba lowo awon oloselu, eoni nisimilorun

  • @AdesIfemi
    @AdesIfemi หลายเดือนก่อน +2

    Eyin OBA alade ema mu inu bi awa odo o dandan ni yoruba nation

  • @labakefunmi7319
    @labakefunmi7319 หลายเดือนก่อน +3

    Queen Naomi go back to your husband because of your son and makes sure Tanikiewo gets another baby's at back

  • @esthyesthy972
    @esthyesthy972 หลายเดือนก่อน

    Why is Oonirisa's orente Temitope feeling very uncomfortable just because of the arrival of Oonirisa's heir Tadenikawo and her mum. Imole de!!!! Okunkun parada!!!!

  • @akinolaflorence7146
    @akinolaflorence7146 หลายเดือนก่อน

    A p c loba wa ooooo

  • @Kanjuabenko
    @Kanjuabenko หลายเดือนก่อน +3

    Lol,okunrin ni omo yi ni abi obinrin

    • @olajumokeaworeni5882
      @olajumokeaworeni5882 หลายเดือนก่อน

      Okunrin ni.

    • @Kanjuabenko
      @Kanjuabenko หลายเดือนก่อน +2

      @olajumokeaworeni5882
      Thanks you, boya dada ni irun re nigbayen

    • @NETWORKTVSHOW22
      @NETWORKTVSHOW22 หลายเดือนก่อน

      Ọkùnrin ní 😊

    • @esthyesthy972
      @esthyesthy972 หลายเดือนก่อน

      🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣 Okunrin ni ooooo!!! Se nitori irun ori re. Dada ni lati ojo ti a bi!!! Olowo eyo, Dada akoja!!!!

    • @Kanjuabenko
      @Kanjuabenko หลายเดือนก่อน

      @esthyesthy972
      Aa e seun , dada lo ba de 😀😀😀