BI AYALEGBE BA FẸẸ FI ILE TO RẸNTI SILẸ, EYI LAWỌN OHUN TO GBỌDỌ ṢE LABẸ OFIN

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 4 ต.ค. 2024
  • We speak for the yorubas in South-West Nigeria, Benin Republic, Brazil, Togo and every other country where we have the yoruba race...

ความคิดเห็น • 14

  • @labakeowolabi2828
    @labakeowolabi2828 2 หลายเดือนก่อน

    Very informative... Ẹ kú iṣẹ́ sir

  • @florencebeauty7322
    @florencebeauty7322 3 หลายเดือนก่อน

    E ku eto sir ,ibeere mi ni wipe se osu mefa tan ma fun ayalegbe lati kuro ni ile je ofe ni abi o ni lati sawon osu mefa yen ti won fun Ese.

  • @mustaphaodeshina5111
    @mustaphaodeshina5111 3 หลายเดือนก่อน

    Good program

  • @alabaadejumo535
    @alabaadejumo535 2 หลายเดือนก่อน +1

    Ẹ́JỌWỌ, ÒFÌN ÈWÒ NÍ Ẹ SÒRÒ NÍPÁ RẸ̀? ÌLẸ́ YÒRÙBÁ TABÍ TI NIGERIA.? Ẹ̀ ṢẸ́ SIR.

    • @akinakinniyi4372
      @akinakinniyi4372 2 หลายเดือนก่อน

      Òfin tí ayalegbe tí Ìpínlẹ̀ Eko, Lagos State Tenancy Law 2011 ni mo sọ̀rọ̀ nípa rẹ. Gbogbo ilé tó bá wá ní Ìpínlẹ̀ Eko ni òfin yìí wá fún.

  • @moriyamooyenuga6656
    @moriyamooyenuga6656 3 หลายเดือนก่อน

    Oun to ye ki e boju to e ko boju to se eni ti ko San owo dede ni won ma fun ni osu mefa tori pe oti San owo odun kan lekan

  • @IfemiSunny
    @IfemiSunny 3 หลายเดือนก่อน

    Ti onile o ba fun ayalegbe ni gbendeke osu to ye ko fun nko, kini ayalegbe na yio se.

    • @akinakinniyi4372
      @akinakinniyi4372 2 หลายเดือนก่อน

      Irú onile bẹẹ ti ṣẹ asofin nìyẹn, idà òfin máa gé lọwọ. Kò sọ́nà miran lábẹ́ òfin tí onile fi lè lé ayalegbe jáde ju kò fún un ní Quit Notice lọ. Ilé ẹjọ nìkan ló lágbára láti kó ẹrú ayalegbe kúrò nínú ilé. Bí onile bá gba ọna ẹburú láti kó ẹrú ayalegbe jáde fúnra ara rẹ, ẹ̀wọ̀n lo fi ń ṣeré.

  • @AdebayoOmowunmiS
    @AdebayoOmowunmiS 3 หลายเดือนก่อน

    Ejowo sir leyin osumefa yen Se tenant masanwo Ile tabi konisanwo

    • @akinakinniyi4372
      @akinakinniyi4372 2 หลายเดือนก่อน

      O di dandan kí ayalegbe san gbogbo owó tó jẹ́ onile pátápátá, ki o tó ko jáde nile laidin kọbọ kan.

  • @DaudaAduranitemi
    @DaudaAduranitemi 3 หลายเดือนก่อน

    Se oma sanwo tabi koni sanwo

    • @rasheedalabi3273
      @rasheedalabi3273 3 หลายเดือนก่อน

      E ma fún ní iwe ti owo rẹ bá tí ku osu mẹ́fà ko tan ní. Gẹ́gẹ́ bí ati ye mi

    • @akinakinniyi4372
      @akinakinniyi4372 2 หลายเดือนก่อน

      O di dandan kó sanwó.

  • @abduljeliliolododo6494
    @abduljeliliolododo6494 3 หลายเดือนก่อน

    Inside one, three or six months that tenant will pay for that month