CCC Hymn 276 || Eba wa yo ara ninu Kristi || C.C.C Holy Spirit Parish Choir ||
ฝัง
- เผยแพร่เมื่อ 6 ก.พ. 2025
- #CCC
#CelestialChurchOfChrist
Follow Celestial Church of Christ Holy Spirit Parish UK ON:
☞Facebook: / sheffieldholyspiritparish
☞Instagram: / holyspiritparishuk
With Majestic Music
CCC for life
God bless CCCW/W 🌈🌈🌈🌈
May subuana WataAllah continue to strengthen the mighty power of celestial ....I am a Muslim but I don't discriminate...God bless from Italy
Alléluia 😘💪
1: Ẹ ba wa yọ, ara ninu Kristi, Fun o ri rere ta ni,
Wakati buburu na de,
Ti o mu aiye yi gbona,
Ẹlẹsẹ ronupiwada, Ni ijọ Mimọ yi.
2: Ogbun nla si silẹ nisisiyi, Lati t’eruku jade,
Bo ko ba fẹ jẹni egbe,
Si ọdọ Olugbala Rẹ,
Rọmọ Kristi ‘nu Ijọ Mimọ yi, Yio ran o lọwọ.
3: Laipẹ, baba ki yio mọ ọmọ, Tab’ ọmọ mọ baba rẹ,
K’aiye silẹ sa tọ Kristi,
O duro loke Mimọ Rẹ, Rukerudo ‘parun nla mbọ,
Ya ronupiwada.
4: Mo si tun nduro ninu anu mi, Npe awọn ẹlẹsẹ,
Wakati yi ẹ pawada,
Laipẹ anu yio dopin,
Fi ‘ka, ajẹ, orisa silẹ, Kristi yio, gba wa la.
5: Gbogbo ẹkun aiye ti sẹ si mi, Sibẹ nko bikita,
Nko ro ẹwa ti Ọrun,
Kika ni irun yin,
Lomu Emi Kristi jiya na, Emi ni, wa, ki o ye.
6: Niti iparun ti aiye yi, Mo fi anu fa sẹhin, Sibẹ aigbagbọ npọsi, Nwọn nsin orisa, ajẹ, Nwọn lo arakan ati ika, Fi wọn lẹ wa ‘dọ Mi.
7: Mo ti pese ohun rere fun ọ,
Ade didan iye na
Bugbe re nduro de o
Lori ile didara na
F’ aiye sile wa sodo Mi
Emi o tewogba o
Amin
The spirit of our father sbj oshoffa will never depart from ur life ijn❤❤❤
May God continue to strengthen his church...
🙌🏾🙌🏾🙌🏾🙌🏾
Happy belated harvest 😇😇😇
(**correction: This is “E ba wa yo ara ninu Kristi” not “Jesu ti joba”)
You need to listen again