Oro yio le pupo ma Ayomiposi ni Oro Adun sun kunkun fun Olohun siti ba Adun na se o ti di olomo laye Oko nikan ni Adun yio ma kiri Bai Nipa Omo iyen ti kuo
Awa omo eniyan ni lati ni Olorun Oba pelu otito tinu-tinu! Iji aye maa nyi enirere mole. The drift of of this world can bring down the righteous somebody, if care is not taken into consideration
O ga ooo Imran mi fun Ayomiposi nipe ko se nkan ti Olatokunbo so fun oooo e seun pupo olusotan wa lakaye yin koni pare lase olohun Aamin
Ese olotu fun itan olowo iyebiye yi Olohun abawa se alekun imo ati oye yin Amin ❤❤❤
Eku eto opolo yin koni joba lase edumare
Very interesting story ❤❤
Thank you sir, may Allah continue to strengthen you.
These is getting serious oo
God bless you sir
Oro yio le pupo ma
Ayomiposi ni Oro Adun sun kunkun fun
Olohun siti ba Adun na se o ti di olomo laye
Oko nikan ni Adun yio ma kiri Bai
Nipa Omo iyen ti kuo
Awa omo eniyan ni lati ni Olorun Oba pelu otito tinu-tinu! Iji aye maa nyi enirere mole.
The drift of of this world can bring down the righteous somebody, if care is not taken into consideration
🎉🎉🎉🎉
Hmmm oga oo
Aanu Olohun koni ka kuro lori Ile Ise yi
Aabo Olohun yio so faju lori gbogbo Eyin Osise ibe
❤❤❤
Thank you so much 🙏 good bless you 🙏
Eseun pupo, Ile ise yi koni baje o,oluwa atunbo ma so agbara dotun
Thank you so much sir❤
Haaaa itan yin ni Agbara
Thanks ❤❤
🎉🎉🎉❤
O serious o
Edun Okan mi
Eku,ise,olotu
Hummmm so sad
❤❤❤