Àṣírí OSOLE

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 26 ธ.ค. 2021

ความคิดเห็น • 4

  • @TheGentleBoy1
    @TheGentleBoy1 ปีที่แล้ว +14

    Ti e ba nsoro e ma yannn!.. Se gbogbo osole ni kodara ni,, ati wipe se AWO niyin nii,, imon wo ni eni nipa osole? Orisirisi osole ni nbe! Oso gbigbona ni kodara, Oso ti oba ti ni nkan eniyan ninun, kodara osi ni atunbotan! Atipe ile aiye ogun ni,, idanileko yin dara pupo sugbon e tun nfi osi owo daapo!. Kosi eniyan ti kole se osole, sugbon iru Oso woni e fe se gan,, se oso gbigbonA ni tabi Oso tutu,,? Awon osole kan nbe ti oje wipe ase Olodumare gannn ni,, sugbon e KO se alaye yinn ni ekunrere, tii eniyan ba dake ti ara re naa yio ba dake, iwo ti o ba ni ise aje re lowo ti nkan osi jorawon dada, Osole tio mu irorun wa lai si wahala kankan nbe, Osole ti nyi aiye eniyan pada si rere, kii se gbogbo osole ni kodara o,, ire o

  • @GODSTECH.C
    @GODSTECH.C 20 วันที่ผ่านมา

    Humm oro nla ati gbagbe kádàrá ati gbagbe ori, awa leè kodoro ati wàláà kakiri

  • @user-pz7bk5kf7f
    @user-pz7bk5kf7f 10 หลายเดือนก่อน +1

    Baba ko ni baje fun yin oo

  • @ayinla4sure135
    @ayinla4sure135 9 หลายเดือนก่อน

    Mix up is much in your auido. We got your point, we should be careful in search of blood money but you didn't tell us not all money ritual are with blood. Osole has categories, pap tutu is different from Oso gbígbóná or Akọ Oso