ASIRI TU :

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 16 พ.ย. 2024

ความคิดเห็น • 22

  • @HannahAdesope
    @HannahAdesope หลายเดือนก่อน +2

    Muideen, asiri e tu,ti e ba o alaimore o ya jewo ko ma🎉ba sewon

  • @christianaholopade8690
    @christianaholopade8690 หลายเดือนก่อน

    Ajiyinrere Muyideen. Senior Evangelist. Find peace. It’s good for you.

    • @james_smith9
      @james_smith9 หลายเดือนก่อน

      Emmanueli dey his name too

  • @yekeenolawepo1841
    @yekeenolawepo1841 หลายเดือนก่อน +1

    Aiye Muyideen ti baaje patapata bayi o.

  • @AdebayoOmowunmiS
    @AdebayoOmowunmiS หลายเดือนก่อน +1

    Enduro Nan iya muideen nko nan sekole seise abiamon Ni tabi abiagba Niya muideen Yi Ni ogaooo

  • @babatundeogunkola1327
    @babatundeogunkola1327 หลายเดือนก่อน +1

    Ko si aniani, muyideen yoo sewon olojo gbogboro.

  • @monisolakehinde4873
    @monisolakehinde4873 หลายเดือนก่อน

    Muyideen ibada KO tete ronu piwada ..or else ewon re niwajue yio

  • @julianaomolayo5454
    @julianaomolayo5454 หลายเดือนก่อน

    Muyeeden, gbe enu re sohun, ta lo wa paro ninu iwo ati Ibukun bayi nitori Olorun. Ta lo wa se e bayi iwo Muyeeden, o ti e ro ri e wo rara. Can't you sit down and think of your life one day. O ga o.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 หลายเดือนก่อน +3

    Olusola Yusuf gbe quran jade kio wa fi bura tio ko ba gba owo lowo awon ota pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel. Olusola iwo na jade kio wa fi quran jade ti okunrin miran ko ba e sun leyin oko re tio bimo fun...

  • @akinsolakunle-t5h
    @akinsolakunle-t5h หลายเดือนก่อน

    Werey nii bobo yii sha😂

  • @funmibadejo3403
    @funmibadejo3403 หลายเดือนก่อน +1

    E maagbo oro buruku lenu were ti ori e ti daru, tiwon ba bi muyideen da ,ko ma lo appear ni court, ara ti nfu muyideen o ti npowe mo ara re pe, opin aye on ti sunmo tosi, aye re nlo si opin, ninu bibeli isaiah 33. V1. So wipe. EGBE NI FUN EYIN ABANIJE TI A KO BAJE , ETC. E LO KAA, ORO OLOHUN NI. KO YIPADA. OLUSOLA TI SO WIPE IBUKUN NPE OLOHUN ALANGBA, OLOHUN EKU, OLOHUN EIYE ATI BEEBELO, OLOHUN KO NI JEKI MUYIDEEN BE IBUKUN , O TI BA NKAN JE KOJA IJOKO ALAAFIA, OTI SO PE ON MAA TA AGBALA GABRIEL, KO RI GABRIEL TA , OLUSOLA, AJIGINI, ATI AWON ALABOSI PARAPO LO MAATA DANU.

  • @AdebayoOmowunmiS
    @AdebayoOmowunmiS หลายเดือนก่อน

    Aye muideen yitibaje patapata anti oponun adugbo tonikogba letter iboni omafi ojusibayi nan ogaooo

  • @babatundeogunkola1327
    @babatundeogunkola1327 หลายเดือนก่อน +1

    Oloriburuku ni muyideen, katikati lo ku to n so . Aanu oluwa ti fi e sile.

  • @AwolopeChristiana
    @AwolopeChristiana หลายเดือนก่อน

    We are hearing

  • @olajumokeaworeni5882
    @olajumokeaworeni5882 หลายเดือนก่อน +1

    Muideen ati olusola lo ni epe. Ijoba esu ni muideen ti wa. Esu ni muideen gangan. Ko mo ju iro lo. Ki muideen naa fi quran bura ti o ba je iro l'oun npa. Abanije lasan ni muideen. E jeki o lo s'ewon. Ibiti o fit e niyen.

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 หลายเดือนก่อน +2

    Muyideen gbe quran jade si social media kio wa bura bi ti lbukun ..iro ti ba tie je Muyideen

  • @florenceadedeji3858
    @florenceadedeji3858 หลายเดือนก่อน +2

    Popoola Oyenike jade kio wa bura pelu bible bi ti lbukun wipe okunrin miran ko ba e sun leyin oko tio bimo fun.tio ba ko lati bura ikunle awa abiyamo toto loma seku pa e ni agbara olorun amin ase Edumare adabi tio ba je wipe iwo lo gbe Muyideen kuro ni abe bridge nikan loku ase Edumare....

  • @ElizabethOgunsade
    @ElizabethOgunsade หลายเดือนก่อน

    Agrarian ni muyideen nlo