Itan Lehin Iku Aare Afonja 13

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 7 ก.ย. 2024
  • Apá kẹtàlá tí níbi àwọn Ọ̀yọ́ Mèsì ṣe gbabode fún Aláàfin Oluewu àti igbihin wọn pẹlu bí Aláàfin ṣe ló kí Emir Ilorin
    Laji Abbas Whatsapp +2348023687432

ความคิดเห็น • 11

  • @yusufsaheedadewale7751
    @yusufsaheedadewale7751 4 ปีที่แล้ว +3

    Oluko agba, the best historian of our time

  • @Ayodeleist
    @Ayodeleist 4 ปีที่แล้ว

    Ese o Oluko Agba. Olorun a gbo adura yin sir. E ku ise naa pelu.

  • @adeagboaremu1019
    @adeagboaremu1019 4 ปีที่แล้ว

    A dupe lopolopo lowo yin fun ise ribiribi ti e n se lori Iran Yoruba. E seun o. Awon Yoruba bo, won ni; “ ina esisi kii jo ‘ni leemeji” sugbon awa Yoruba ko mu owe yi lo rara nitori ina esisi yi ti n jo iran Yoruba bo lati ojo pipe. Ina esisi yi kanna si n jo wa lowolowo bayi nitoripe a ri awon eniyan ti won n tako idasile Amotekun fun ile Yoruba ati ipolongo ipe fun idasile ori’le ede Ominira Oduduwa. Ina esisi ti koja igba egberun meji t’o ti n jo wa. A si pa owe lo jasi o fun awa ti a ni owe naa.

  • @santamorestrengthinyourarm9412
    @santamorestrengthinyourarm9412 4 ปีที่แล้ว

    Nibo ni IBARAPA ti sewa sir

  • @wosilatamosu9017
    @wosilatamosu9017 4 ปีที่แล้ว

    Laji Abbas Eku Ise opolo well ka kii gbogbo Awon ti se biribiri ni ti dada fun Yoruba Sugbon Tobe jubelo EMI tenu mo wipe Asiko ti to lati parapo jagun igbasile awa Yoruba sile Oba mi oke yio Bawa yanju ré ASE 🙏

  • @femipope18
    @femipope18 4 ปีที่แล้ว +1

    Mo fe mo itan ijebu ode ati Ijebu ososa

  • @thickbarbieskitchen1159
    @thickbarbieskitchen1159 4 ปีที่แล้ว

    Eku ise oo

  • @olajideisola8594
    @olajideisola8594 4 ปีที่แล้ว +1

    E se pupo oluko agba, pelu gbogbo ogun ni le yoruba se Aresa ati Olugbon ko kopa kankan no?

  • @crownedking2567
    @crownedking2567 4 ปีที่แล้ว

    Gbogbo oro won yi jeki mo pe Oogun "Medicine" ko ran Ogun "war".
    Olootu Abbas,ki lo de ti Alaafin Oyo o se kansi awon ti Ondo ati Ekiti parapo pelu awon Ijebu fun iranlowo lati bori emir Ilorin?