Congratulations to Governor Engr.Seyi Makinde for acting so wisely and nobly to appoint the right Alafin for the good of all Yorubas.God bless Seyi Makinde, God bless Oyoland, God blessYoruba land and all its people .Yoruba Nation, no going back.
Bi awon ijoba elekunjekun ati awon oba wa ba feran ara won ati eniyan ti won wa ni abe ijoba won ki won se eto bi Sunday Igboho yio se papa wa sile. E jeki o sise ti Olorun ran, e si fun un ni gbogbo eto re patapata. Yoruba Nation, no going back.
Baba,sorosoro ,e wi ire. Drardara yin a ma dara sii ni. Ki ijoba jowo ki won gba Sunday Igboho wole pelu ife.Alafia ati ife a papa si ile Yoruba lagbara Eledumare
Mr Omiyale, what do we do with this our Kings? Why would Timi of EDE go to Emir of Ilorin only to kneel down to greet him. Are we sure some of this Kings are not Fulani.
Omo oko tooto, ki Olorun Olodumare tubo fun omo Adeyemo ni okun ati agbara , ati aabo to peye fun oun ati awon omo ogun re pelu atileyin awon alale ile yoruba
I can not comprehend the type of human beings that are leaving at this particular town Iwo ?for tolerating the type Oba with his gangsters running down the people of Iwo town .
To ba ni omo yoruba ogidi to fe gbabode ni akoko yi fun omo adeyemo awon alale ile yoruba fi eje nwon, omi ara nwon, ati Iran ara gbogbo nyin patapata se irubo ati etutu fun ile yoruba
Ki nwon gba ko wole laini tun fi le awon ota re lowo leekeeji, ki Olorun Olodumare ati awon alale ile yoruba tubo dabobo omo adeyemo ati gbogbo awon omo ogun re patapata
CSIA,God is fighting your battles in Jesus mighty name Amen 🙏 😅😅😅😅❤❤❤.
Congratulations to Governor Engr.Seyi Makinde for acting so wisely and nobly to appoint the right Alafin for the good of all Yorubas.God bless Seyi Makinde, God bless Oyoland, God blessYoruba land and all its people .Yoruba Nation, no going back.
God bless you my brother igboho osha Owo baba dami
Ti wọn bati free Baba wa,cati gbogbo awọn Ọmọ Yoruba Atata pátá pata
Wa alaeykum ssalam warahmatullohi wabarakaatuhu
Bi awon ijoba elekunjekun ati awon oba wa ba feran ara won ati eniyan ti won wa ni abe ijoba won ki won se eto bi Sunday Igboho yio se papa wa sile. E jeki o sise ti Olorun ran, e si fun un ni gbogbo eto re patapata. Yoruba Nation, no going back.
Baba,sorosoro ,e wi ire. Drardara yin a ma dara sii ni. Ki ijoba jowo ki won gba Sunday Igboho wole pelu ife.Alafia ati ife a papa si ile Yoruba lagbara Eledumare
Good job Mr omiyale,ko ni baje fun yin ni ase edumare
ASE ASE ASEWA
Mr Omiyale, what do we do with this our Kings?
Why would Timi of EDE go to Emir of Ilorin only to kneel down to greet him.
Are we sure some of this Kings are not Fulani.
Chief Sunday Adeyemo igbowo Ekun oko fulani
Igboho osha Owo baba dami
Chief Sunday igboho is more important than Reuben abat in Yoruba land
Osha baba
Kì LON she Àwọn GOVERNOR ILE YORUBA, kí wọn Ronú o
E ku ise na sir ile yoruba a gbe wa o
Aseo aribe ajebe alolease
Omo oko tooto, ki Olorun Olodumare tubo fun omo Adeyemo ni okun ati agbara , ati aabo to peye fun oun ati awon omo ogun re pelu atileyin awon alale ile yoruba
I can not comprehend the type of human beings that are leaving at this particular town Iwo ?for tolerating the type Oba with his gangsters running down the people of Iwo town .
Ku laakaye bàbá
Ki won gbe rasheed iwo,ati mufti iwo , ati imam Ogbomosho
Eku Eto
Ààmìn
Omiyale 1 koni baje fune lailai
To ba ni omo yoruba ogidi to fe gbabode ni akoko yi fun omo adeyemo awon alale ile yoruba fi eje nwon, omi ara nwon, ati Iran ara gbogbo nyin patapata se irubo ati etutu fun ile yoruba
Ki nwon gba ko wole laini tun fi le awon ota re lowo leekeeji, ki Olorun Olodumare ati awon alale ile yoruba tubo dabobo omo adeyemo ati gbogbo awon omo ogun re patapata
Ijoba laju sile awon fulani terrorise yoruba bayi se won fe so wa di ode ni tan ni ka ma ja fun ra wa ki awon fulani ma ha le mo wa.