Baba! You know who are flagging your program every time. Awon brothers yin in Islam. Nobody can be so docile to reject knowledge. You are an academician. God will bless and preserve you sir.
Gbe fun, Aare opitan. E ku ise opolo. Beere yin o ni toro aforiji lori itan ilorin to so toripe sultan Sokoto lo fowosi iwe ki o to di Mudiru Morikaz ko si fe padanu aaye naa. Idi niyi ti o fi nsegbe lehin Fulani. Sugbon ko ye mi bi Sultan Sokoto yio se ma yan Mudiru Marikaz Agege fun ile Yoruba.
Nkan ti awon ilu to ku ni gbogbo agbaye se nfi oju ole ati odaran wo gbogbo awa omo Nigeria 🇳🇬 niyen. Nigbati eniyan ba ra nkan ni toro, ti e so wipe ko mu pound 💷 kan wa ki e to fun ni eru re to fi owo ara re ra pelu gbogbo owo ti eleru ti san fun alabaru to ba gbe eru. Ti ijoba si ti gba eto tiwon lowo alabaru. O ga ooooooo.
Please, let's all bloggers help us to carry out this message to custom office and let's all Nigerian and overseas know the cheating of our Nigerian custom
This story of how emir killed Yoruba warriors he used them against one another. It is similar to to the fight between Aare opitan, Gani Adams and Igboho Osha. Please settle your fights

Ameen
It is Fulani Ilorin Alfas, pure Yoruba Muslims can't do that
Kudos ,mo gbee fun Aare Opitan ooo,Haaa,ise nla ni e nse seooo.eseun gan niooi.Sugbon emi fe ki Aare maa fi itan wonyi se awon iwe kale ooo.
🙏 ẹku isẹ takuntakun sir
Aare God bless you and your household
Kudos to you Ààrè laji Àbàss
Gbe fun, Aare opitan. E ku ise opolo. Beere yin o ni toro aforiji lori itan ilorin to so toripe sultan Sokoto lo fowosi iwe ki o to di Mudiru Morikaz ko si fe padanu aaye naa. Idi niyi ti o fi nsegbe lehin Fulani. Sugbon ko ye mi bi Sultan Sokoto yio se ma yan Mudiru Marikaz Agege fun ile Yoruba.
Baba you really know Ina sir
I really proud of you sir ❤️ 👏 ♥️
Nkan ti awon ilu to ku ni gbogbo agbaye se nfi oju ole ati odaran wo gbogbo awa omo Nigeria 🇳🇬 niyen. Nigbati eniyan ba ra nkan ni toro, ti e so wipe ko mu pound 💷 kan wa ki e to fun ni eru re to fi owo ara re ra pelu gbogbo owo ti eleru ti san fun alabaru to ba gbe eru. Ti ijoba si ti gba eto tiwon lowo alabaru. O ga ooooooo.
Bless you Aarę. Eseun gbogbo igba.
Aare Opintan , Itan nio nitooto .
Oro nipa owo sise ati yoruba...
❤️❤️❤️👑❤️❤️❤️Aare You're A Blessing To Our Great Tribe 🙏🏽
Iwaju, iwaju ni opaebiti yin yoo mo resi. Amin ati gbogbo wa lapapo.
Well-done sir
Good job. Welldone, sir.
Please, let's all bloggers help us to carry out this message to custom office and let's all Nigerian and overseas know the cheating of our Nigerian custom
Oro phone yi, enito gbe adie otosi o ti gbe talaroka o. 😂😂😂
E ku ise takuntakun Aare opitan ile yoruba
Iyeni wipe, awon Esho dabi awon ninja Japan
Eku Ise Ooooo baba ti wa
Dey PLAY
E ku ise opolo
EKUSE TAKUNTAKUN
Please what’s the name of Timi of ede of that time that died at war cuz I’m a prince from ede town prince to Timi lalemon 5th king of Ede town
Kila ma se lori oro phone Aare eyin Ọmọ Yoruba?
Eku ise opolo Aare
Eku ise
Opolo
You don`t have to pay for the phone, the phone had been paid for before leaving united Kingdom. DHL had been paid where is the expenses came from.
Aare
This story of how emir killed Yoruba warriors he used them against one another. It is similar to to the fight between Aare opitan, Gani Adams and Igboho Osha. Please settle your fights
@ LAJI Emilokan can help you collect your phone. Just give him a call , I hope you are enjoying your own breakfast’s