NAIRA MARLEY - GIDDEM (LYRICS)

แชร์
ฝัง
  • เผยแพร่เมื่อ 8 ต.ค. 2024
  • ‪@NairaMarley‬ giddem lyrics video
    #musiclyrics #giddemlurics #fypシ゚viral
    #lyrics
    [Intro]
    Yo-
    Big Vibez
    [Verse 1]
    If to say na me be you
    If I see Naira Marley
    Ma ya sare se twale
    I go ask baba for way
    Because igi imu jina s'ori
    Ọmọ ma ra ko to rin
    Sanmọ o le wa lẹ
    Ẹjẹ kan mo pe sanmọ o le wa lẹ
    Oju ra wọn lọ
    O skingba kan ju kan lọ
    A nọ gbe fun kan ju kan lọ
    Mo lo n bẹ bi kan ju kan lọ
    [Pre-Chorus]
    And it's all on God (And it's all on God)
    That we are still on top
    Anything they like make them talk
    Ohun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ
    O ti ṣẹlẹ bayi
    Oti di agbo awọn werey bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (Hello)
    O ti ṣẹlẹ bayi
    Oti di agbo awọn werey bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (Hello)
    [Chorus]
    To ba funmi Dollar, ma gba
    To ba funmi Naira, ma gba
    Pounds ma gba
    To ba funmi l'owo, ma gba
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    [Verse 2]
    Ayebo, ayeba
    Somebody call the popo
    Baba ibeji, iba jojo
    T'emi ba k’ọri, k'iwọ ma jo
    Ayebo, ayeba
    Somebody call the popo
    Baba ibeji, iba jojo
    Temi ba k’ọri, k'iwọ ma jo
    O le tẹ go mọlẹ, ma lọ t'agba mọlẹ
    Igo ma n ya yan l'ẹsẹ
    Agba ma surprise ẹ
    Basically agba ma n ya yan l'ẹnu
    [Pre-Chorus]
    And it's all on God (And it's all on God)
    That we are still on top
    Anything they like make them talk
    Ohun to ba wun ẹlẹnu lo le sọ
    O ti ṣẹlẹ bayi
    Oti di agbo awọn werey bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (Hello)
    O ti ṣẹlẹ bayi
    Oti di agbo awọn werey bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi
    Wọn ti price kẹ ya ma bọ bayi (Hello)
    [Chorus]
    To ba funmi Dollar, ma gba
    To ba funmi Naira, ma gba
    Pounds ma gba
    To ba funmi l'owo, ma gba
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    Giddem, giddem, gidden, giddem
    [Outro]
    Big Vibez

ความคิดเห็น •