- 78
- 4 716
IKOKO ASA TV
เข้าร่วมเมื่อ 26 ส.ค. 2022
Lórí ìkànnì yìí, a ó máa kẹ́kọ̀ọ́ lórí :
Àwọn àṣà Yorùbá lọ́kan ò jọ̀kan
Òwe Yorùbá lóríṣiríṣi
Àwọn Ọba Aládé nílẹ̀ Yorùbá
Orúkọ Yorùbá
Òǹkà Yorùbá
Àkànlò èdè Yorùbá
Òǹkà Yorùbá
Àkànlò èdè Ayàwòrán
Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
Àwọn àṣà Yorùbá lọ́kan ò jọ̀kan
Òwe Yorùbá lóríṣiríṣi
Àwọn Ọba Aládé nílẹ̀ Yorùbá
Orúkọ Yorùbá
Òǹkà Yorùbá
Àkànlò èdè Yorùbá
Òǹkà Yorùbá
Àkànlò èdè Ayàwòrán
Àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
ohun gbogbo ni yóò tán , Ọlọ́run nìkan ni yóò kù .
ohun gbogbo ni yóò tán , Ọlọ́run nìkan ni yóò kù .
มุมมอง: 11
วีดีโอ
bàtá dance
มุมมอง 272 หลายเดือนก่อน
Try the free video editor CapCut to create videos! www.capcut.com/t/Zs8hDEVoX/
Bàtá dance during opening ceremony of Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá Nàìjíríà , Ọ̀YỌ́ 2024
มุมมอง 132 หลายเดือนก่อน
Bàtá dance during opening ceremony of Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá Nàìjíríà , Ọ̀YỌ́ 2024
HAPPY 50TH BIRTHDAY to you dear sister TAIWO ADEDOKUN
มุมมอง 63 หลายเดือนก่อน
HAPPY 50TH BIRTHDAY to you dear sister TAIWO ADEDOKUN
Ẹni tí ó se ọbẹ̀ àtẹ́ tí a ní kí òrìṣà pa á ,ẹni tí kò wá sè ńkọ́ ?
มุมมอง 43 หลายเดือนก่อน
Ẹni tí ó se ọbẹ̀ àtẹ́ tí a ní kí òrìṣà pa á ,ẹni tí kò wá sè ńkọ́ ?
Ẹ jẹ́ kí á tún igbá ilé ṣe , torí pé a kò mọ̀ bóyá ti oko yóò gbó
มุมมอง 73 หลายเดือนก่อน
Ẹ jẹ́ kí á tún igbá ilé ṣe , torí pé a kò mọ̀ bóyá ti oko yóò gbó
Ẹni tí yóò jẹ oyin inú àpáta, kò ní í wo ẹnu àáké
มุมมอง 153 หลายเดือนก่อน
Ẹni tí yóò jẹ oyin inú àpáta, kò ní í wo ẹnu àáké
Àmín àse. Oga mi, e kú ohùn. Òdodo òrò pónbélé tó gba ìronújinlè àti ìmúlò. E seun,opolo yín o ní d'óbà l'áse Èledùmàrè.
Àṣẹ Èdùmàrè àti tiyín náà o
E ku igbelaruge asa egbe Akomolede ko ni baje lase edumare
E kú ìgbéláruge àsà nínú egbé. Orírun Yóòbá á gbè yín,l'áse Èledùmàrè. Àmín àse.
Congratulations and happy birthday.🎉🎊🎂🎈🎁❤🍒
Baba, e kú ohùn opolo yín o ní d'óbà l'áse Èledùmàrè.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ o
Òdodo òrò pónbélé. E kú ohùn.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ o
Baba, e kú ohùn. Àgbà yín yóò d'alé l'áse Èdùmàrè.
Àmí lórúkọ Jésù
E kú ohùn, opolo yín o ní d'óbà l'áse Èledùmàrè. Àmín.
Àṣẹ Èdùmàrè
E kú ohùn, àgbà kò ní tán lórí ilè l'áse Èledùmàrè. Àmín.
E kú ohùn, e kú isé takuntakun. Á jú yín se .
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ ìyá mi àtàtà
Kini Ajaa kole ni ohun agogo lenu. Kini ape ni Ajaa
Kogo Kogo làá gbógun agogo , kerejegbe lohun akèrègbè ,bí ó ti wù kí akèrègbè tóbi tó ko lè lóhùn agogo lenu
Òdodo òrò pónbélé. E seun o.
Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ yín
Àmín àse Elédùmurè. E kú ohùn. Àgbà kò ní tán lórí ilè l'áse Èledùmàrè.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́
Àṣẹ Èdùmàrè . Ẹ ṣeun ìyá mi àtàtà
E kú àkíyèsí àti àtúnse. Àgbà kò ní tán lórí ilè. Èdè Yorùbá kò ní parun l'áse Èledùmàrè.
Aginde ara yio make o.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun bàbá mi
Béèni ògá mi, a ní láti ponmi s'ílé de òùngbe.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ ìyá mi àtàtà fún ìdásí yín
You are doing well sir 🤍🙏
Thanks
Àmín àse Kírístì. E kú ohùn. E sì kú ìgbìyànjú. Àsà àti ìse Yorùbá kò ní párun l'ólá Èlédùmàrè. Olúwa Yóò máa kún yín fún ogbón, e ò ní t'enu gbó bí owò l'áse Èdùmàrè. Àmín àse.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun ìyá mi àtàtà
Ewa ede eku kiki eku kiki bami eledumare
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ bàbá mi
Nice one, more grease to your elbow
Amen
More wisdom baami❤❤❤
Amen
❤❤❤❤❤
Thanks
Kú isé opolo. Òdodo òrò. Eni to bá tá bà, kí ó tún ibè se.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ ìyá mi àtàtà. Ẹ ó pẹ́ fún wa láṣẹ Èdùmàrè
Eku koleda,ikoko Asa ko ni fo lase Edumare.
Àṣẹ Èdùmàrè ìyá mi
E kú isé opolo, e kú ìgbéàsà ga. Èlédùmàrè á gbé wa ga. Àsà Yorùbá kò ní párun ní àse Èdùmàrè.
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ ìyá mi àtàtà
O káre, Omo Yorùbá àtàtà, kú isé opolo. Ìjìnlè òrò tí ó kó ni l'ógbón àti èkó tó jinlè, tó yè kooro. Opolo re kò ní dóbà ní àse Kírístì.
Ẹ ṣeun fún idasi yín ìyá mi àtàtà
E ku ojumo oooo
Ẹ káàárọ̀ bàbá mi nínú Olúwa
Mo un gbadun re
Ẹ ṣeun bàbá mi nínú Olúwa
The gift of man will make a way for him
Thanks for your concern sir
Òdodo òrò, ìfunra loogùn àgbà. Kí a kíyèsí ara.
Ẹ ṣeun fún idasi yín ìyá mi àtàtà
E ku ise takutaku
Ẹ ṣeun fún idasi yín bàbá mi
Olúwa seun
Ẹ kú ohùn !
Ẹ ṣeun fún idasi yín
Kú isé opolo, Adaniwaye Yóò pelu re nínú gbogbo àdáwólé re. Àse Èdùmàrè. Yóò jú o se o.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun fún idasi yín ìyá mi
Òdodo òrò. O káre baba mi kékeré. Anikun ogbón Olórun. Àse Èdùmàrè.
Ẹ ṣeun mo mọ rírì ìdásí yín ìyá mi àtàtà. Ẹ ó pẹ́ fún wa láṣẹ Èdùmàrè
Ẹ kú ìṣe sir
@@estherosunkunle2942 Ẹ ṣeun ṣeun
Eku ise baba
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ fún dídarapọ̀ mọ́ wa. Mo mọ rírì yín o.
Ê kú isé opolo bàbá mi
Ẹ ṣeun
Hummmm, bẹẹni ooo, ẹ kú làákàyè bàbá mi
Ẹ ṣeun fún ìdásí yín
Ẹ ku ohun
Ẹ ṣeun
Ẹ kú isẹ́ sir
Ẹ ṣeun fún ìdásí yín
Esehu pupo baba wa
Ẹ ṣeun fún ìdásí yín
Olorun ama fun se ooo eku ise
Ẹ ṣeun ìyá mi fún ìdásí yín
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́
O káre Omo Oko. Ààre ti ìjìnlè. Opolo re ò ní dóbà. Àse Èdùmàrè.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun ìyá mi Àtàtà
Kú isé opolo. Opolo re kò ní dóbà l'áse Èdùmàrè. Àmín.
Àṣẹ Èdùmàrè. Ẹ ṣeun ìyá mi àtàtà
Esé sa
Ẹ ṣeun mo dúpẹ́ fún ìfẹ́ yín
Ààrẹ Òjó, ẹ kú iṣẹ́ takuntakun!
Ẹ ṣeun ṣeun fún ìdásí yín bàbá mi.
Ẹ kú iṣẹ ọpọlọ, ẹ kú ìgbélárugẹ èdè abínibí.
Ẹ ṣeun mo mọ rírì ìdásí yín bàbá mi
Ẹ kú ohùn, àmì ọgbọ́n yín ò ni fọ́.
Àṣẹ Èdùmàrè àti ẹ̀yin náà
*àmù ọgbọ́n
Love this
Thanks
Wise
Impresive